settings icon
share icon
Ibeere

Ki ni adura elese?

Idahun


Adura elese je adura enia I an gba si Olorun nigba ti won ba mo wipe elese ni awa a si fe irapada. Gbigba adura elese ko je ohun pataki. Adura elese se pataki ti e ni naa bam on itumo re, ti o ba ni oye re, ti won si gbagbo ninu ese naa fun irapada.

Ohun kini ninu adura elese ni wipe a ni lati mo wipe elese ni wa. Romu 3;10 wipe, “Gege bi a ti ko o pe, ko si eniti nse olododo, ko si enikan. Elese ni gbogbo wa, anu ati idariji ese ni a bere lowo olorun (Titu 3:5-7). Nitori ese wa, iya ayeraye lo to si wa (Matteu 25; 46). Adura elese je geg bi ibere fun anu bi ko se iya ayeraye. Eyi ni ofi je gege bi anu lai je wipe ibinu Oluwa.

Ohun keji adura elese ni wipe ohun ti Oluwa ti se fun wa, lati rawa pada lowo ese ayeraye. Oluwa gbe awo omo eniyan wo, o si di eleran ara, Jesu Kristi (Johannu 1; 1, 14). Jesu ko wa ni otito nipa Olorun, nitori o ti fi i se ese nitoriwa, eniti ko da esekese ri i, (Johannu 8;46; 2 Korinti 5;21). Jesu si ku fun wa lori igi agbelebu, o si gba es ti o ye wa (Romu 5;8). Jesu jinde ninu oku lati fi isegun han lori ese, oku ati ijoba apadi (Kolosse 2; 15; 1 Korinti ori 15). Nitori eyi, Oluwa le dariji ese wa ati fun ileri iye ainipekun ni paradise. Ti a ba le fi igbagbo wa le Jesu Kristi. Ohun ti a ni lati se ni ki a gbagbo wipe o ku fun wa, o si jinde ninu oku (Romu 10;9-10). A le ni irapada nipa anu re, pelu igbagbo nikan, ninu Jesu Kristi nikan. Efesu 2; 8 wipe, “Nitori ore-ofe li a ti fi gba nyin la nipa igbagbo, ati eyi ni ki ise ti enyin tikaranyin, ebun Olorun ni.”

Gbigba adura elese je gege bi ona ti a n gba lati so wipe o fi gbogbo igbesi aye re le Jesu Kristi lowo gege bi olugbala. Ko si si gbolohun oso to ja si igbala. Igbagbo ni iku ati ajinde Jesu ni kan lo le gba o la. Ti iwo ba mo n wipe elese ni o, o si fe igbala ninu Jesu Kristi, gba adura elese yi si Oluwa ; “ Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se Oluwa, fun irapada ese mi! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Ki ni adura elese?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries