settings icon
share icon
Ibeere

Se Jesu nikan ni ona naa si orun?

Idahun


“Emi je enia daradara, nitori naa emi yio lo si orun.” Gege bee, mo ti se awon ohun buburu sugbon mo se ohun rer to ju buburu lo, gege be, emi yi lo si orun.” “Oluwa o ni ran mi lo si orun apadi nitori pee mi o gbe igbesi aye mi bi bibeli se wi. “Awon ti o se buburu gan bi awon ti o n ba omode lopo tabi apaniyan ni o lo si orun apadi.”

Eyi je ohun ti awon eniyan ma n so, otito be ni wipe, oniro ni gbogbo won. Satani, eni ti o joba okunkun aye, fi eyi si wa ni ori. Ohun ati awon ti o n tele je ota Oluwa (1 Peteru 5:8) satani a ma paro fun awon enia pe ohun dara (2 Korinti 11:14), sugbon o ni agbara lori awon ti ko si ninu Oluwa. “Satani, oba awon eni buburu ni ile aye yi, o si ti fi ohun bo okan awon ti o gbagbo, nitori naa won ko le ri imole ogo iroyin ayo re ti o tan lori won. Won ko ni oye nipa iroyin naa nipa ogo Kristi, to je eni gege bi Olorun (2 Korinti 4:4).

Iro ni a pa ti a ba nip e Oluwa ko fara si ese kekere, wipe orun apadi wa fun eni buburu. “Gbogbo ese ni o muwa jina si Olorun, eyi ti o kere gan ni (Romu 3; 23). Li lo si orun wa ki se nipa ohun daradara wa ti o leke ohun buburu wa: A o segbe to ba je be ni. Ti awa pa de ti ni irapada nipa anu oluwa “Nitori naa ki se nipa ise daradara owo wa. Nitori naa, anu Oluwa ko ni je ohun ti oje- ominira ati aini” (Romu 11:6). Ko si ohun rere ti a le se lati wo orun (Titu 3;5).

Iwo le wo paradise nikan si ona toro. Ona orun apadi sit obi gan, ati wipe opolopo enia ni o le wo be (Matteu 7; 13). Nje ti iwo ba n gbe igbesi aye elese, ti o si ni ireti ninu tasere, Oluwa ko ni je ko wole. Igbesi aye re ko yato si awon enibuburu, elese, satani ni o tele, alagbara ninu ategun. Eyi ni ti on sise ninu okan awon ti o gba Oluwa gbo.” (Efesu 2; 2).

Nigbati Oluwa da ile aye, o dara gan. Gbogbo re ni o dara. O si da Adamu ati Efa, o si fun won ni ominira won lati le se ohun ti won ba fe ti won ba fe tele Olorun ki won si pa ofin re mon tabi rara. Sugbon Adamu ati Efa, awon enia Olorun akoko, satani si tan won lati ma pa ofin oluwa mon, won si dese. Eyi mu won jina si oluwa ( ati awon ti o wa leyin won pelu awa) lati ni ibasepo pelu Oluwa. Oluwa dara, mimo ni, o si ma dajo elese. Bi elese a ko le ra ara wa pada. Nitori naa, Oluwa fe ara ye gege to be, ti o si fun wa ni omo re kan soso fun wa, wipe enikeni ti o ba gbagbo ko ni segbe sugbon ebun Oluwa ni iye ainipekun (Johannu 3:16). Iku ni ere esewa, sugbon ebun oluwa ni iye ainipekun ninu Jesu Kristi oluwa wa. (Romu 6:23). Jesu wa si aye ki o ba le ko wa ni ona naa, o si ku fun ese waki awa je eni irapada. Leyin ojo meta nigbati o ku, o jinde lati inu issa oku (Romu 4; 25), o si pese idande ati igbala lori oku. O si rawapada ki awa le wa pelu Oluwa lati ni Ibasepo pelu Oluwa ti awa ba ni igbagbo.

Ona yi ni a file gba iye ainipekun- “ki a mo n o, oluwa ayeraye, Jesu Kristi ti o ran wa si ile aye” (Johannu 17;3) awon enia ni igbagbo ninu Oluwa, satani gan ni. Sugbon ki agba igbala, a ni lati gba Olorun gbo, ki a si sumo, yipada kuro ninu ese re, ki o si tele. A ni lati ni ireti ninu Jesu pelu igbagbo ohun ti a ni ati gbogbo ohun ti a n se.

Awa se ohun idande ni oju Oluwa ti awa ba ni ireti ninu Jesu Kristi lati gbe ese wa kuro. Nitori naa awa le di eni irapada, enikeni ti a baje, tabi ohun ti a se” (Romu 3;22). Bibeli so fun wa wipe ko si ona miran fun igbala afi Kristi nikan. Jesu wipe ni Johannu 14; 6, “Emi ni ona, otito ati iye. Ko si eni ti o wa si odo baba bi ko se nipase mi.”

Jesu ni kan ni ona igbala nitori pe ohun ni kan ni o le mu ere ese wa kuro (Romu 6;23). Ko si esin miran ti o ko wa gidigidi nipa gan ese ati iye rre. Ko si esin miran ti o fihan nipa irapada ese wa bi Jesu Kristi ti se funwa. Ko si awon “elesin dida sile” miran ti o fihan wipe Oluwa di eleran ara( Johannu 1:1;14)- ona kan ti gbese wa fi le di sisan. Jesu di Olorun lati san gbese wa. Jesu ni lati di eleran ara lati ku fun wa. Igbala wa fun eni ti o gbagbo ninu jesu Kristi! Ko si igbala ninu elomiran, ko si oruko miran ti won fun wa ni abe orun fun igbala omo eniyan afi fun igbala nikan” (Ise Awon Aposteli 4: 12).

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Se Jesu nikan ni ona naa si orun?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries