Ibeere
Nje Jesu ni Olorun? Nje Jesu wipe ohun ni Olorun?
Idahun
Jesu o so fun wa pato ninu iwe Bibeli wipe, “Emi ni Olorun.” Eyi o si wipe ki se Olorun. Ti a ba wo Johannu 10;30, “Emi ati Baba mi, okan ni wa.” Ti a ba koko wo, ko da bi wipe ohun ni Olorun. Sugbon, ti a ba wo awon ara ju, bi won se wi, “Awa ko so li okuta nitori ise rere, sugbon nitori oro-odi; ati nitori iwo ti ise enia n fi ara re se Olorun” (Johannu 10;33). Awon Ju gbo oro Jesu ti o fi wipe ohun ni Olorun. Ni ese iwe mimo yi, Jesu ko jiyan pelu awon Ju lati wi fun won wipe, “Emi ni Olorun.” Eyi fi han wipe Jesu fi ye wa wipe ohun ni Olorun, “Emi ati Olorun okan ni wa” (Johannu 10;30). Johannu 5;58 fi han wipe, loto, loto ni mo wi fun nyin, ki Abrahamu to wa, emi niyi.” Leyin na awon Ju fe so ni okuta (Johannu 8: 59). Ki ni idi ti awon Ju fe so Jesu ni okuta ti ko ba je wipe o so oro-odi ti won mon, bi Emi ni Olorun?
Johannu 1;1 wipe, “Olorun si ni oro naa.” Johannu 1;4 wipe, “oro naa si di enia.” Eyi fi han wipe Jesu ni Olorun eleran ara. Ise awon aposteli 20;28 wipe, ‘ ………. Ti emi mimo fin yin se alabojuto re, lati ma toju ijo Olorun, ti o ti fi eje ara re ra. Tani o ra ijo naa pelu eje re? Jesu Kristi. Ise awon aposteli 20;28 so wipe, Oluwa ra ijo re pada pelu eje re. Nitori naa, Jesu ni Oluwa!
Tomasi omo leyin Jesu wipe, “Oluwa mi ati Olorun mi” (Johannu 20;28). Jesu si jiyan re. Titu 2;13 so fun wa wipe, ki a duro de igba keji ipadabo Olorun Olugbala- Jesu Kristi (wo 2 Peter 1;1). Heberu 1;8, Baba fi omo re Jesu han. Sugbon nipa ti omo o wipe, ite re, Olorun, lai ati lailai ni, o pa alade ododo li opa alade ijoba re.
Ninu ifihan, angeli so fun Johannu wipe Olorun nikan ni ki o fi oriba fun (Ifihan 19;10). Lorisirisi ona ni Jesu te rib a ni ninu iwe mimo (Matteu 2;11, 14;33, 28;9,7, Luku 24;25, Johannu 9;38). Ko si ni ki awon enia ki won ma se sin ohun, gege bi angeli ninu Ifihan. Awon iwe ori miran ati ese miran ninu Bibeli fi ye wa nipa Jesu Oluwa.
Idi pataki ti Jesu ni lati je Olorun ni wipe, ti ko ba je Olorun, iku re ko ni to be ge lati san gbese ese gbogbo aye (1 Johannu 2;2). Olorun ni kan ni o le san iru gbese ayeraye naa. Olorun nikan ni o le rue se gbogbo aye (2 Korinti 5;11), iku ati ajinde. Ti o si joba lori ese ati iku.
English
Nje Jesu ni Olorun? Nje Jesu wipe ohun ni Olorun?