Ibeere
Ibo ni Jesu wa ni ojo meta larin iku ati ajinde?
Idahun
1 Peteru 3;18-19 wipe, “Nitoriti Kristi pelu jiya lekan nitori ese wa, oloto fun awon alaisoto ki o lemu wa de odo Olorun, eniti a pa ninu ara, sugbon ti a so di aye ninu emi: Ninu eyiti o lo pelu, ti o si wasu fun awon emi ninu tubu.”
Oro na, “pelu ti emi,” ni ese 18 ri bakanaa pelu oro naa, “ninu ti ara.” Nitorinaa o dara ki a so wipe oro naa “emi” gege bi oro naa “ara” li ara ati emi je ti ara ati emi Kristi. Oro naa si di alaye nipa (ninu) emi, “ese ti Kristi gbe ati iku re si di ipinya emi ara lati odo Baba (Matteu 27;46). Iyato naa ni ara ati emi, bi Matteu 27:46 ati Romu 1;3-4, lai se pe larin ara Kristi ati Emi Mimo. Nigbati Kristi gbe ese wa naa tan, emi re si ra wa pada pelu Olorun.
Peteru kini 3;18-22 fihan nipa iya ti Kristi je (ese 18) ati ogo re (ese 22). Peteru nikan ni o so fun wa nipa re. Oro naa “wasu”ni ese 19 ki se oro ti a lo lati fi han ninu Majemu Titun gege bi iwasu oro Olorun. Itumo re ni wipe akede oro. Jesu jiya o si ku lori igi agbelebu, a si pa, emi re si ku nigba ti a sodi elese. Sugbon emi re si was aye, o si gbo ohun Baba. Bi Peteru se so. Larin iku re ati ajinde re, Jesu si wa ninu ipo “ti emi tubu.”
Ki a fi bere, Peteru ni wipe, “okan” ki se “emi” (3;20). Ninu Majemu Titun, oro naa “emi” a ma n lo fun awon angeli tabi esu, ki se ti eniyan; ese 22 si so fun wa. Nitori naa, ko si ohun ti o so fun wa ninu Bibeli pe Jesu lo si orun apadi pada. Ise Awon Aposteli 2;31 wipe o lo si “ipo oku” (iwe Bibeli Amerika), sugbon “ipo oku” ki se apadi. Ipo oku je ibi ti awon oku n lo, ibi ti won yio wa fun igba die ki won to jinde. Ifihan 20;11-15 si fi itumo naa han. Apadi je ibi ti enia o wa titi lai, sugbon isa oku je ibi fun igba die.
Olorun wa fie mi re le Baba re, ko ku ati wipe larin iku ati ajinde re, o si lo si isa oku nibiti o ti fi oro sile fun emi ara (boye awon angeli ti o se; wo Juda 6) awon ti o wa pelu Noa ki omi to gbe won lo. Ese 20 fi han. Peteru ko so fun wa naa ohun ti o so fun awon angeli yi, sugbon ki se oro igbala nitoripe angeli ni won (Heberu 2:16). A si mo wipe isegun ni o so fun won lori satani ati ebi re (1 Peteru 3;22, Kolosse 2;25). Efesu 4;8-10 si so fun wa nipa Kristi wipe o lo si, “Paradise” (Luku 16;20, 23;43) o si lo si orun pelu awon ti o gbagbo ninu iku re. Sugbon ori iwe naa ko so fun wa pupo nipa ohun ti o sele, sugbon awon akowe gbagbo wipe eyi ni a n pe ni “ti a si mu oko eru kuro.”
Ohun ti a n so ni wipe, Bibeli ko so fun wa ohun ti Kristi n se ni ojo meta larin iku ati ajinde re. A mo wipe oro igbala ni o kede fun awon alaigbagbo. Ohun ti a mon ni wipe Jesu ko fun wo ni aye keji lati ri igbala. Bibeli ni wipe a o dajo wa leyin iku (Heberu 9;27), ko si igba keji. A ko mo ohun ti Jesu n se ni ojo meta larin iku ati ajinde re. Boya ohun eyi ni a o mo nigbati awa ba ti wa pelu Olorun.
English
Ibo ni Jesu wa ni ojo meta larin iku ati ajinde?