settings icon
share icon
Ibeere

Ki ni itumo pe ki a gba Jesu Kristi gege bi olugbala wa?

Idahun


Nje iwo ti gba Jesu Kristi geg bi Olugbala re? ki o to le dahun, je ki n dahun ibere naa. Ki a le ni oye ibere naa, o ni lati ni oye nipa“Jesu Kristi”,temi nikan” ati “olugbala.”

Tani Jesu Kristi? Opolopo eniyan ni o so wipe eniyan daradara ni Jesu Kristi, Olori oluko, tabi iranse Oluwa. Gbogbo eyi ni o je otito nipa Jesu, sugbon eyi ko dahun ibere na nipa eni ti Jesu fe. Bibeli so wipe, Jesu je Olorun ninu eran ara, Oluwa si di eleran ara (wo Johannu 1; 1,14). Oluwa wa si ile aye lati wa ko wa, wow a san, fi wa sonar ere, dariji wa- o si ku fun wa! Jesu Kristi ni Olorun, eni to da aye, alagbara Olorun giga. Se iwo ti gba Jesu gbo?

Ki ni igbala, ki lo de ti a fi ni olugbala? Bibeli so fun wa wipe elese ni gbogbo wa, a ti rin ona esu (Romu 3;10-18), nitori ese wa naa, Oluwa si binu si wag an to si to si idajo. Iya ti o to ese ayeraye ti a se si olorun ayeraye wa ni iya ayeraye. (Romu 6: 23; ifihan 20; 11-15). Nitori naa ni ase fe olugbala.

Jesu Kristi wa si ile aye o si ku fun wa. Jesu, iku, Oluwa ni eleran ara, eyi je igbese ese ti a san ti ayeraye (2 Korinti 5;21). Oluwa ku fun wa lati san ere iya ese wa (Romu 5;8). Oluwa san gbese naa ki awa ma le san. Jesu, ajinde re je gege bi iyanu iku re lati le san gbese iya ese wa. Nitori naa ni jesu nikan ni olugabala (Johannu 14;6 : Ise Awon Aposteli 4;12)! Se iwo ni ireti ninu Jesu olugbala?

Nje jesu je gege bi olugbala mi nikan? Awon eniyan ni igbagbo wipe, omo olorun je gege bi eni ti o n lo si ile ijosin, ti o si n rubo, ti ko si da ese. Eyi ko ni omo Olorun. Omo olorun loto je eni kan to ni ireti pelu Jesu Kristi. Gbigba Jesu gbo gege bi olugbala re ni kan jasi wipe iwo ni igbagbo ati ireti ninu re. ko si eni ti o gbagbo ninu eniyan lati ni igbala. Ko si eni eni ti o n dari ji ni fun ohun ko ohun ti o ba se. ona kan ti o le gba lati ri igbala nikan ni ki o gba Jesu gege bi olugbala, ireti ninu iku re fun sisan ese wa ati ajinde re fun iye ainipekun (Johannu 3;16). Se jesu je olugbala re ni kan?

Ti o ba fe gba jesu Kristi gbo gege bi olugbala re nikan, so awon oro won yi si Oluwa. Ranti wipe, gbigba adura yi tabi adura mi ran ko le gba o o la. O ni lati ni ireti ninu Jesu Kristi wipe o le dariji ese re ji o. Adura yi je eyi ti o file so fun Oluwa nipa igbagbo re ninu re, ki o si dupe fun idariji re.“ Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun ore- ofe ati idariji ese mi- ebun ayeraye! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Ki ni itumo pe ki a gba Jesu Kristi gege bi olugbala wa?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries