settings icon
share icon
Ibeere

Tani Jesu Kristi?

Idahun


Tani Jesu Kristi? Ko da bi ibere, “Nje Oluwa wa?”Awon eniyan die ni o ti bere wipe nje Jesu Kristi wa. A gba wipe Jesu je enia ti o wa si ile aye lori ile Isreali lati igba jinjin. Ibere naa bere leyin igba ti won ni tani Jesu. Gbogbo esin ni o so wipe Jesu je alarina, oluko tabi omo Olorun. Aimoye ibe ni wipe, Bibeli ki se alarina, oluko gidi tabi omo Olorun nikan.

C. S. Lewis ninu iwe re Kristiani nikan ko wipe: Mi o fe ki enikeni so gege bi omugo bi awon ti on soro nipa re (Jesu Kristi); “emi gba pe Jesu ni Oluko gidi, sugbon emi ko gba pe Oluwa ni. Eyi ni a ko gbodo so. Enia ti o je enia ti o so ohun ti Jesu so, ko le je Oluko gidi. A le pe ni alai ni opolo- omo enia ti o so wipe eyin ni ohun – tabi esu lati orun apadi. Mo eyi ti o fe se. tabi ara kunrin yi je omo Olorun tabi eni ti ori re ko pe….. o le pe ni asiwere, iwo le tuto si, ki o si pa bi esu; tabi ki o kun le ki o sip e ni Olorun Oluwa. E ma se je ki a soro nip a pe oluko enia daradara ni. Ko ti so fun wa be. Ko de so fun wa naa.

Tani Jesu je? Kini Bibeli so nipa re? Ni akoko, e je ki a wo oro Jesu ni Johannu 10;30, “Emi ati Baba mi okan niwa.”Ti a ba wo, eyi le ma je pe o pe rare ni Oluwa.. Sugbon e wo awon ara ju bi won se soro, “a ko ni so o e loko, wipe awon ju, sugbon nipa oro odi si Olorun nitori pe enia lasan ni o”(Johannu 10;33). Awon ju mo nipa Jesu, oro re nipa ara Ju. Eyi fi han wipe Jesu ni Oluwa, “Emi ati Baba mi okan ni wa”(Johannu 10;10). Johannu 8;58 fihan naa. Jesu wipe, “Loto loto ni mo so fun yin, ki Abrahamu to wa, emi ti n be! Pelu re naa awon ara Ju mu oko won si fe so fun (Johannu 8;59), Jesu soro nipa ara re, “Emi ni”Eyi fi han ninu iwe Majemu (Eksodu 3;14). Ki ni o de ti awon ara Ju fe so Jesu ni okuta, ti ko ba je wipe o so oro odi wipe ohun ni Olorun?

Johannu 1;1 wipe, “oro naa si ni Oluwa.”Johannu 1;14 wipe, “oro naa si di enia.”Eyi fi han wipe Jesu ni Olorun ninu eran ara. Tomasi so fun Jesu. “Oluwa Olorun mi”(Johannu 20;28). Jesu ko si jiyan re. Aposteli Paulu so nipa re pe, Oluwa alagbara, olugbala wa, Jesu Kristi”(2 Peteru 1;1). Olorun Baba mo nipa Jesu, sugbon nipa omo re o wipe, “Ite re Oluwa, titi ayeraye ni ati ododo re ni ibugbe re. “Iwe Majemu so nipa Kristi, “Nipa ti eyi, a si bi omo kan si ti wa fun wa, gbogbo orile ede yio si wa lori apa re. a o sip e ni olugbala, Olorun alagbara, baba titi lailai, onifokan bale.

Bi C.S Lewis ti so, gbigba Jesu gege bi oluko ki se ijiyan rara. Jesu so wipe ohun ni Olorun. Ti ko ba se Olorun, oniro si ni ki de se oluso, oluko daradara, tabi omo Olorun. Ki a le tumo oro Jesu, awon akowe so wipe ko si oto ninu Bibeli nipa ohun ti Jesu pe ara re. Tani wa lati jinyan pelu oro Olorun nipa ohun ti Jesu se tabi ti ko so? Ba wo ni awon amowe se ma jinyan tabi yio kuro ninu oro re won a si wipe won mo nipa Jesu fun ohun ti o so ati eyi ti ko se ju awon ti o gbe pelu re, ti won sin, ti Jesu si ko won (Johannu 14;26)?

Ki lode ti ibere nipa Jesu fi je Pataki? Ki lo de ti o fi je didan lati so wipe Jesu ni Olorun tabni ki se Olorun? Eyi ti o se Pataki lati mo wipe Jesu ni lati je Olorun ni wipe ti ko ba n se Olorun. Iku re ki ba n se ohun ti o le san ese fun gbogbo aye (Johannu 2;2). Olorun nikan ni o le san gbese naa (Romu 5;8, 2 Korinti 5;21). Jesu ni lati je Oluwa lati le dariji wa. Jesu ni lati di enia lati ku. Igbala wa ninu igbagbo ninu Jesu Kristi! Ibere naa ni wipe, ki lo de ti o fi je wipe Jesu nikan ni igbala wa. Ki lo de Jesu se so wipe, “Emi ni ona, otito, ati iye ainipekun. Ko si eni ti o wa si odo baba mi bikose nipa ese mi”(Johannu 14;6).

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Tani Jesu Kristi?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries