settings icon
share icon
Ibeere

Kini a n pe ni eni atubi ninu Kristi?

Idahun


Kini a n pe ni eni atubi ninu Kristi? Ninu iwe bibeli li o dahun ibere yi ni Johannu 3;1-21. Jesu Kristi Oluwa n ba Nikodemu soro, eniyan pataki farasi ati ara sadusi (Olori alufa Ju). Nikodemu wa si odo Jesu ni ale, Nikodemu ni ibere lati bere lowo Jesu.

Jesu si ba Nikodemu soro, o wipe, “….. loto loto ni mo wi fun o, bikosepe a tun enia bi, o nko le ri ijoba Olorun”. Nikodemus so fun Oluwa.” A o ti se le tun enia bi, nigbati o di agbalgba tan? O ha le wo inu iya re le lo nigba, keji, ki a si bi? Jesu wipe, loto loto ni mo wi fun o, bikose a fi omi ati emi bi enia, o n ko le wo ijoba Olorun. Eyiti a bi nipa ti ara, ara ni, eyiti a si bi nipa ti emi, emi ni. Ki o ma se ya yin lenu, nitori mo wi fun o pe, a ko le se alaitun nyin bi……..” (Johannu 3;3-7).

Gbolohun “Eni atunbi” so ni soki wipe “eni ti a bi lati orun wa” Nikodemu fe lati se. o fe tun okan re rapada- emi irapada. Omo titun, eni atubi, eyi ohun ti oluwa fi si le to je wipe iye ainipekun wa fun eni ti o ba gbagbo ( 2 Korinti 5;17, 1 Peteru 1;3, 1 Johannu 2;29, 3;9, 4;7, 5;1-4,18) Johannu 1;12,13 so wipe “atubi” si fihan wipe ki a je Omo Olorun” inu igbagbo ninu oruko Jesu Kristi.

Ibere naa wa soki, “ki lo de ti a ni lati je atubi? Aposteli Paulu ni Efesu 2;1 so wipe, enyin li o si ti so di aye nigbati enyin ti ku nitori irekoja ati ese n yin…….” Fun awon ara Romu ni Romu 3; 23, awon aposteli ko wipe, gbogbo enia li o sa ti se, tin won si kuna ogo Olorun. “Nitori naa, enia ni lati je atunbi ki idariji wa fun gbogbo ese wa ati lati ni iba sepo pelu Olorun.

Ba wo ni o se je? Efesu 2;8,9 wipe “Nitori ore-ofe li a ti fi gba iyin la nipa igbagbo ati eyi ni ki ise ti enyin tikaranyin; Ebun Olorun ni ki ise nipa ise, ki enikeni ma ba sogo. “To o ba ti ni “igbala”, o ti di atubi, idokun ninu emi, o ti di omo Olorun nipa itumo.” Nini igbagbo ninu Jesu Kristi, eni ti o raw a pada lowo iya ese wa nigba ti o ku lori igi agbelebu, eyi ni a n pe ni atunbi ninu emi. “Nitori naa bi enikeni ba wa ninu Kristi, o di eda titun; Ohun atijo ti koja lo; kiyesi i nwon si di titun” (2 Korinti 5;17a).

Ti o ba ti ni igbagbo ri ninu Oluwa Jesu Kristi geg bi Olugbala, se o le gba emi mimo laye ninu okan re? O ni lati je atunbi. Se o gba adura idariji ese ki o si je enia titun ninu Kristi ni oni? Sugbon iye awon ti o gba a awon li o fi agbara fun lati di omo Olorun, ani awon na ti o gba oruko re gbo; Awon eniti a bi ki ibe nipa ti eje, tabi nipa ti ife ara, beni ki ise nipa ife ti enia, bikose nipa ife ti Olorun” (Johannu 1;12-13).

Ti o ba fe gba Jesu Kristi gege bi olugbala. Ki iwo si je atunbi, eyi ni adura soki.Ranti wipe, gbigba adura yi tabi adura mi ran ko le gba o o la. O ni lati ni ireti ninu Jesu Kristi wipe o le dariji ese re ji o. Adura yi je eyi ti o file so fun Oluwa nipa igbagbo re ninu re, ki o si dupe fun idariji re.“ Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun ore- ofe ati idariji ese mi- ebun ayeraye! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Kini a n pe ni eni atubi ninu Kristi?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries