Ibeere
Kini itumo ile aye yi?
Idahun
Kini itumo ile aye yi? Ba wo ni mo sele ri itumo re, iroyin, ati imuse ni ile aye yi? Nje mo ni ile aye yi? Nje mo ni agbara lati se ohun gidi? Opolopo ni won si tun bere wipe kini itumo aye yi. Won si wo igbesi aye won, won si bere wipe ba wo ni ile aye won se ri bayi. Won bere lowo ara kunrin kan wipe, ‘Ki ni won so fun nigba ti o koko bere si ni gba bolu. O so wipe, ‘won ba ti so fun ohun wipe yi omo eniyan baa ti de oke nla, ko si ohun kohun nibe.”Orisirisi igbese aye raye fi ofo han leyin opolopo odun ti won ti fi segbe.
Ninu ile aye yi, awon omo eniyan ni won fe di gidi, ti won si ro wipe awon le ni itumo. Eyi je gege bi ise ayeyori, ola, ebi gidi, ibasepo, ohun irorun ki a si ma se daradara si enikeni, etc. Awon eniyan wipe ti awon ba ni igbagbo eyi, sugbon iho kan ti wa ninu aye won…. Ko si ohun ti o le di.
Eni ti o ko iwe iwasu wipe, “ofo! ofo!...... ofo na ni ! Gbogbo ohun ni ofo. “Eni ti o ko yi ni ola gidigidi. Oni oye ju omo eniyan, obinrin ni ogorun, ile ati ohun ogbin ti o wu awon oba miran loju, onje ati oti, ati ohun iyalenu. O si so wipe ni akoko kan, ohun ti okan re ba fe, yio si wa. O si wipe, ile aye labe orun, “( Igbesi aye bi ile aye ni a le ri pelu oju wa ati ohun ara wa) ofo ni! Kilo de ti eyi se je be? Nitori pe Oluwa da wa lati le ri ohun isin yi. Solomoni so fun Olorun wipe, “o si ti fi ayeraye si okan omo enia…..”Ninu okan wa, awa mo wipe ni isinsinyi ki se ohun nikan.
Ninu iwe Genesisi, a mo wipe Oluwa da wa ni ara re (Genesisi 1;26). Eyi je wipe a da bi Oluwa (ohun kohun ti oni emi). A si mo wipe nigba ti awa eniyan si ti dese, awa ohun wo yi si je otito. (1) oluwa da omo eniyan pelu ohun gbogbo (Genesisi 2; 18-25): (2) Oluwa fun omo eniyan ni ise (Genesisi 2;15); (3) Oluwa ba omo eniyan joko(Genesisi 3;8); ati (4) Oluwa fun omo eniyan ni gbogbo aye (Genesisi 1; 26); Kini eyi je? Oluwa fe je ki a gbe ayerere sugbon ese wa ni o dina dewa (Genesisi 3).
Ninu iwe ifihan, leyin ohun orisirisi ti yi o sele, Oluwa ni ohun yio pa aye re bob a je orun ni isin yi tabi aye yi, ohun yio si fi orun ati aye titun mi han. Nigba naa yi o si fi ogo re han pelu awa omo eniyan. Awon omo eniyan miran yi o si ti lo si orun apadi ( Ifihan 20;11-15). Ko si ni si ese mo, ibanuje, aisan, iku, irora etc (ifihan 21;4). Awon onigbagbo yi o si jeer re; Oluwa yi o wa pelu won, won si je omo re (Ifihan 21;4). A si mo wipe Oluwa da wa lati sin; omo, fun wa ni ohun gbogbo lati le se ohun ko kun (Luku 23;43). Sugbon ile aye yi je daradara. Sugbon ba wo ni ile aye ati orun yi sele je tiwa?
Itumo ile aye nipa ti Jesu Kristi
Bi a se so tele, itumo ona yi ni a le ri pelu ibasepo wa pelu Oluwa ti a ti segbe tele pelu Adamu ati Efa nipati ese won. Loni, ona ti a file rawapada nikan ni nipa ti Olorun ti o je omo re, Jesu Kristi (Ise Awon Aposteli 4;12 ; Johannu 14; 6 ; Johannu 1;12). Ile ayeraye ni a le rigba ti a ba gba idariji ese (ti a ko fe rin ona naa sugbon ona Kristi ki a di titun). Ki a gbekele Jesu Kristi gege bi olugbala wa ( wo ibere naa “Kini ona igbala?”lori oro yi).
Itumo ile aye yi ko le ri ninu Jesu Olugbala (Bi o ti dara to). Sugbon, itumo ile ni a le ri ti a ba ti n bere si ni tele Kristi gege bi omo leyin re, mo nipa re, nipa oro re, Bibeli, ma gba adura, rin pelu re gege bi ofin re. Ti iwo ba je alaigbagbo (tabi o sese je atunbi) iwo le bere, eyi ko dun mo mi rara!”Sugbon ka iwe Bibeli si. Jesu so wipe,”E wa sodo mi gbogbo enyin ti nsise, ti a si di eru wuwo le lori, emi o si isimi fun nyin. E gba ajagba mi si orun nyin, ki e si ma ko eko lodo mi; nitori oninu tutu ati onirele okan li emi; enyin o si ri isimi fun okan nyin. Nitori ajaga mi rorun, eru mi si fuye.”(Matteu 28-30). “Nitorina ni nwon wi fun u pe, Ne oju re ti se la”Johannu 10;10). Nigbana ni Jesu wi fun awon omo-ehin re pe, Bi enikan ba nfe lati to mi lehin, ki o se ara re, ki o si gbe agbelebu re, ki o si ma to mi lehin. Nitori enikeni ti o ba fe gba emi re la, yio so o nu; Sugbon enikeni ti o ba so emi re nu nitori mi, yio ri i”Matteu 16; 24-25). “Se inu-didun si Oluwa pelu, on o si fi ife inu re fun o”(Orin Dafidi 37;4)
Ti gbogbo ese yi ba n so fun wa ohun ti o ye ka se. A le ma rin ona wa fun ara wa (ki a si ma rin ni ofo) tabi ki a tele Oluwa ati ona re pelu okan wa (lati le ni igbesi aye rere ati di dara). Nitori pe Oluwa wa ni ife wa, o si fe aye rere fun wa (Sugbon igbesi aye to o ni ona otito).
Ti a ba fe, mo fe so ohun kan ti oluso aguntan kan so, ti iwo ba fera ere ori papa. Ti iwo ba si lo si ori papa lati lo woran, iwo le ri orisirisi ohun ibanuje ni ibi ti iwo ba joko si nitori owo kekere ti o san sugbon ti o ba san owo nla, iwo le joko si ibi ti ko ni ija ati ariwo. Be naa ni o se ri pelu igbesi aye wa. Lati ri ise Oluwa, ki se ijo isimi nikan. Won ko ti san naa. Riri Oluwa ninu ise re, pelu gbogbo okan omo leyin Kristi lati se ohun ti Oluwa fe. Won si ti fi ara won fun Kristi; won si n gbe igbese aye gidi lati le fihan omo eniyan, Oluwa wipe aye won dara. Nje iwo ti yipada? To ba je be, ebi ayeraye ki yio pa o mo.
English
Kini itumo ile aye yi?