Ibeere
Kini awon ofin emi merin naa?
Idahun
Awon ofin emi merin yi je ona ti a le soro fun awon eniyan nipa iroyin ayo igbala ti o wa fun igbagbo ninu Jesu Kristi. Eyi je ona pataki ti a pin iroyin ayo naa si ona merin.
Ofin emi merin kini ni, oluwa feran re osi ni igbesi aye ti o dara fun o .Johannu 3;16 wipe, “Nitori Olorun fe araiye to be ge, ti o si fi omo bibi re kansoso funni, ki enikeni ti o ba gba gbo ma ba segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun. Johannu 10;10 fun wa ni idi ti Oluwa fi wa, “emi wa kin won le ni iye, ani kin won le ni lopolopo.” “Ki ni ohun ti on denaa de wa ta ni ife Olorun?” Ki ni o dena a de wa lati gbe igbesi aye wa ni daradara.
Ofin emi merin keji ni, ese je ohun etan fun omo eniyan, o si je ki a jina si Oluwa. Nitori naa, a ko le mo Ohun didara ti Oluwa ni fun wa. “Romu 3;23 fihan wipe, “Gbogbo enia li o sa ti se, ti nwon si kuna ogo Olorun. Romu 6;23 fi iya ese wa han, iku ni ere ese. “Oluwa da wa ki awa le ma kegbe rin pelu re.” Sugbon awa omo enia dese, e yi si je ka pinya pelu Olorun. Awa ti ba iba se po na je pelu Olorun ti o ni fun wa. Ki ni atuse?
Ofin emi merin keta ni, Jesu ni kan ni olegbawa la lowo ese. Nipa ti Jesu Kristi nikan ni a le gba idariji ese ki awa si ni ododo ibasepo pelu Oluwa. “Romu 5;8 wipe, “Sugbon Olorun fi ife o n papa si wa han ni eyi pe, nigbati awa je elese Kristi ku fun wa. “1Korinti 15; 3-4, so fun wa, ohun ti o ye ki a mon, ki a si gbagbo lati ni irapada, “…..wipe Kristi ku fun ese wa bi bibeli ti wi, wipe won sin, o si jinde ni ojo keta bi iwe mimo ti wi…… . Jesu fun ra ra re wipe, ohun ni ona otito, iye ninu iwe Johannu 14;6.” Jesu wi fun u pe, “Emi ni ona, otito ati iye; ko si enikeni ti o le wa sodo Baba, bikose nipase mi.” “Ba wo ni mo se le gba ebu daradara igbala yi?”
Ofin emi merin kerin ni, a ni lati fi igbagbo wa sinu Jesu Kristi gege bi olugbala wa lati gba ebun igbala, ki a si mo ohun dardara ti oluwa ni fun igbesi aye wa. “Johannu 1;12 wi fun wa wipe,” “sugbon iye awon ti o gba a, awon li o fi agbara fun lati di omo olorun, ani awon na ti o gba oruko re gbo. Ise Awon Aposteli 16;31 fi han, “gba Jesu Kristi Oluwa gbo, a o si gba o la”. Awa le ni igbala nipa ore-ofe, nipa igbagbo ni kan ninu Jesu Kristi nikan (Efesu 2;8-9).
Ti iwo ba fe ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala re, so oro yi si Oluwa. Nipa siso oro yi ko le gba o la, sugbon ireti ninu Kristi nikan. Adura ni soki yi je gege bi ona ti a fi le han Oluwa wipe awa ni igbagbo ninu re, awa ti dupe fun ipese igbala naa.“ Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun ore- ofe ati idariji ese mi- ebun ayeraye! Ami!
Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.
English
Kini awon ofin emi merin naa?