Ibeere
Kini Bibeli so nipa oti mimu/ waini? Nje ese ni fun kristiani lati mu oti/tabi waini?
Idahun
Iwe mimo ni orisirisi ohun ikilo fun oti mimu (Lefitiku 10;9, Numeri 6;3, Deuteronomi 29;6, Onidajo 13;4, 7;14, 1 Samueli 1;15, Owe 20;1, 31;4;6, Isaiah 5;11,22;24;9, 28;7, 29;9, 56;12, Mika 2;11, Luku 1;15). Sugbon iwe mimo ko so wipe ki kristiani ma mu oti waini tabi ogogoro miran. Awon ori iwe mimo miran soro nipa ati ni daradara. Oniwasu 9;7 pa ni ase wipe, “ maa fi inu-didun mu oti waini re.” Orin Dafidi 104;14-15 wipe Olorun fun wa ni waini “ti yi o si mu inu enia dun.” Amosi 9;14 soro nipa oti mimu lati inu ogba gege bi ibikun Olorun. Isaiah 55;11 wipe, “beni, ra waini ati wara….. .”
Nkan ti Olorun so fun Kristiani niwipe ki won ma se yo pelu oti (Efesu 5;18). Oluwa ko fe omutipara ati iwa re (Owe 23;29-35). Kristiani o si gbodo fi ohunkohun ge ara won (1 Korinti 6;12, 2 Peteru 2;19). Omutipara je ohun ti a le ma le fi sile. Iwe mimo si so wipe kristiani mase seohun ti yio bi kristiani miran ninu tabi ti won yio dese (1 Korinti 8; 9-13). Bi a ti se so, ko si ni da ti kristiani ba ni wipe ohun mu oti lati be Olorun ga (1 Korinti 10;31).
Jesu yi omi waini. O da bi eni wipe Jesu mu waini ni igba miran (Johannu 2;1-11, Matteu 26;29). Ninu iwe Majemu Titun, omi won ko dara. Nigbati ko si bi won se le toju re, omi naa ko si dara. Eyi si je otito ni ilu miran. Nitori eyi awon enia si n mu waini (tabi eyi ti a fi eso se) nitori pe o dara. Ni Timoteu 5;23, paaulu so fun Timoteu pe ko ma mu omi (nitori pe o ni inu rerun), nitori naa o mu waini. Ni asiko igba yi, a ma n ru, sugbon ki se bi ti ode yi. A le ni eso ni, sugbon a kole so wipe waini ni bi eyi ti o wa loni. Bibeli ko so wipe ki a ma mu waini, tabi oyi miran to ni ogogoro. Ogogoro ko dara, ese ni. Sugbon ki a sa fun wipe ki a mutipara ati aileyipa da lati mu oti. A ni lati sora fun (Efesu 5;18, 1 Korinti 6;120.
Ogogoro, ni mimu ni kekere, ko da fun ara. Awon dokito kan so wipe waini pupa dara fun okan enia, oti mimu fun kekere je ohun ti kristiani ba fe, omutipara ati ailesa fun je ese. Sugbon, bi Bibeli se so nipa ogogoro ati iwa to wa pelu re, wipe a le fe mu ni igba gbogbo- o dara ki kristiani ma se mu oti rara.
English
Kini Bibeli so nipa oti mimu/ waini? Nje ese ni fun kristiani lati mu oti/tabi waini?