settings icon
share icon
Ibeere

Kini Kristiani mo nipa ipara eni? Kini Bibeli so nipa pipa ara eni?

Idahun


Gege bi Bibeli, boya enia pa ara re, eyi ko so wipe yio wo ijoba orun. Ti eni ti ko je atunbi ba pa ara re, orun apadi ni o n lo. Eni ti o si pa ara yio wa ni orun apadi nitoripe o ko igbala Kristi, ki se nitoripe won pa ara won. Bibeli so fun nipa awon marun ti won pa ara won: Abimeleki (Awon Onidajo 9:54), Saulu (1 Samueli 31:4), Eni ti o ru ihamora Saulu (1 Samueli 31:4-6), Ahitofeli (2 Samueli 17:23), Simri (Awon Oba 16:18), ati Judasi (Matteu 27: 5). Okan kan ninu won buru, elemi okuku, ati elese. ( a ko mon pupo nipa Onihamora Saulu lati li so eni ti o je). Awon kan nipe Samsoni wa lara awon ti pa ara won (Awon Onidajo 16:26-31), Sugbon ohun ti Samsoni fe se ni ko pa awon omo filistini, ki se ara re. Bibeli je ki a mon wipe ipara eni dabi ipani yan ni- ohun ti o je niyen. Olorun nikan ni o le so igba ti enia yio ku. Ki o se ohun ti o wu je odi si Olorun.

Kini Bibeli so nipa Kristiani ti o pa ara re? Emi ko gbagbo wipe Kristiani ti o ba pa ara yio padanu igbala re lati lo si apadi. Bibeli wipe ni akoko ti enia ba ti gba Kristi gbo, yio si ni igbala ayeraye (Johannu 3:16). Gege bi Bibeli ti wi, Kristiani lati mo wipe won ni igbala ayeraye fun ohun kohun ti o ba sele. “Nkan wonyi ni mo kowe re si nyin ani si enyin ti o gba oruko Omo Olorun gbo; ki enyin ki o le mo pe enyin ni iye ainipekun, ani fun enyin ti o gba oruko Omo Olorun gbo” (1 Johannu 5:13). Ko si ohun ti o le yawa kuro ninu ife Olorun! “ Nitoripe o da mi loju pe, ki se iku, tabi iye, tabi awon angeli, tabi awon ijoye, tabi awon alagbara, tabi ohun igba isisiyi, tabi ohun igba ti mbo, tabi oke, tabi ogbun, tabi eda miran kan ni yio le ya wa kuro ninu ife Olorun, ti o wa ninu Kristi Jesu Oluwa wa” (Romu 8: 38-39). Ti o ba si je be, “ohun ti o da” le yawa kuro ninu ife re, kristiani ti o ba si pa ara re si je “ohun ti o da” nitori naa, eyi ki yio je ki o yawa lowo ife Olorun. Jesu ku fun ese wa… ti omo leyin Jesu ba si ni isoro ti o si pa ara re- eyi si je ese wipe Jesu ku fun wa.

Eyi fi ye wa pe pipa ara eni je ese gidi si Olorun. Gege bi Bibeli ti so, ipara eni je ipaniyan, ko si dara. Emi yi o si ni iyemeji lati bere wipe eni ti o ni igbagbo ninu Jesu ti o si tun pa ara re. Ko si ohun ti o le je idalare fun enia papa Kristiani to pa ara re. A pe Kristiani lati gbe igbesi aye won fun Olorun- Olorun nikan ni o lo so igba ti enia yio ku, Olorun ni kan ni. Ti a ba wo iwe Esteri, yio si fi han wa nipa eyi. Ni Persia, won ni ofin kan to je wipe eni ti o ba wa si iwaju Oba lai je wipe Oba ni ko wa, won yio si pa afi ti Oba naa ba naa opa re wipe ki won je ko wa. Pipara eni yio dabi wipe a fe ri Olorun fun ra wa lai se pe o pe wa ni asiko tire. O ni lati na opa re si o, ki o si fun o ni iye ainipekun, eyi ko so wipe inu re dun si o. Sugbon won ko fi han, Bibeli so ninu 1 Korinti 3: 15 fihan nipa ohun ti o sele si Kristiani ti o ba pa ara re: “ Eni na yio si ni igbala, sugbon yio dabi eni ti o salo kuro ninu ewu alo ina.”

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Kini Kristiani mo nipa ipara eni? Kini Bibeli so nipa pipa ara eni?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries