Ibeere
Bawo ni mo se le ri idariji gba lati odo Olorun?
Idahun
Ise awon Aposteli 13:34 so wipe, “Nje ki o nyin, ara, pe nipase okonrin yi li a nwasu idariji es fun nyin.
Ki ni itumo idariji ati wipe ki ni iwulo re fun mi?
Oro ti a pe ni “idariji” tumo si wipe ki a to takaada mo, tabi ki a yonu si, tabi ki a pa igbese re.
Ti a ba se enikan, a maa n bere fun aforiji eni yen ki a ba le tun ni ibasepo otun pelu eni naa. A kii ri idariji gba nitori pe o ye fun wa lati rii gba, tori wipe ko tile si enikan ti o ye lati ri idariji gba. Idariji je ifarahan ife, aanu ati ore-ofe. Idariji je ipinnu lati ma ni ikunsinu si enikeni, lai ka iwa ti won ti wu si wa tele.
Bibeli je ki o ye wa wipe, gbogbo wa ni a nilo idariji lati odo olorun. Gbogbo wa ni lati se. Iwe Oniwasu 7:20 so wipe, “Nitoriti ko si oloto enia lori ile ti nse rere ti ko si dese.” 1 Johannu 1:8 so wipe, “ti awa ba ni a ko da ese, a n tan ara wa je ni, ati wipe otito ko si ni inu wa.” Gbogbo ese ni oje iwa ole si Olorun (Orin Dafidi 51:4). Nitori idi eyi, a nilo idariji lati odo Olorun gi di gidi. Ti a ko ba ri idariji ese wa gba, o daju wipe a o lo ayeraye wa ninu iya nitori awon ese ti a ti da (Matteu 25:46; Johannu 3:36).
Idariji – Bawo ni mo se le rii Gba?
A dupe wipe, Olorun wa kun fun ije ati aanu- o si yara lati dari awon ese wa ji wa! 2 Peteru 3:9 so wipe, Oluwa ko fi ileri re jafara bi awon elomiran iti ka ijafara: sugbon o nmu suru fun nyin nitori ko fe ki enikeni ki o segbe bi kose ki gbogbo enia ki o wa si ironupiwada. Owu olorun lati dari ji wa, nitori re lo fi wa ona fun wa lati le maa ri idariji gba.
Ijiya ti o to fun ese wa ni iku. Abala kinni iwe Romu 6:23 so wipe, “iku ni ere ese wa. Olorun ninu eto re ti o pe di eniyan eleran rar eyi ni Jesu Kristi (Johannu 1:1,14). Jesé ku lori igi agbelebu, o gba iya ese w aje, eyi ti i se iku.
2 Korinti 5:4 ko wa wipe, Nitori aw ti mbe ninu ago yi nkerora nitoto, eru npa wa: ki ise nitori ti awa nfe ije alaiwoso sugbon ki a le wo wa li aso ki iye ki o le gbe ara kiku mi. Jesu ku lori igi agbelebu, o gba iya wa je! Gegebii Olorun, iku Jesu ni o mu idariji wa fun gbogbo ese araye. 1 Johannu 2:2 so wipe, etutu fun ese wa ki si ise fun tiwa nikan, sugbon fun ti gbogbo araiye pelu. Jesé jinde kuro ninu ipo oku, o si kede isegun re lori ese ati iku.(1 Korinti 15:1-28). Ogo ni fun Olorun, tori wipe iku ati ajinde Jesu, gbala keji iwe Romu 6:23 je otito wipe, … Sugbon ebun Olorun ni iye ainipekun nipase Jesé Kristi Oluwa wa.
Se o fe ki a dari ese re jin o? Nje okan re kun fun ero idalebi ti ko see mu kuro? Idariji wa fun o ti o ba fi igbagbo re sinu Jesé Kristi gegebi olugbala re. Efesu 1:7 so wipe, “Ninu eniti awa ni irapada wa ni pa eje re, idariji ese wa, gege bi oro ore-ofe re.” Jesé san igbese fun wa, nitori naa a lee ri idariji gba. Ohun ti o ni lati se nipe, ki o beere fun idariji lati owo Olorun nipase Jesu Kristi, pelu igbagbo pe Jesé ku lati gba idarijifun o- yio si dariji o! Johannu 3:16-17 fun wa ni iroyin iyanu yi wipe, “Nitori Olorun fe araye to bee ge ti o fi Omo re nikan so so fun wa, wipe enikeni ti o ba gbagbo ki o ma ba segbe sugbon ki o le ni iye ainipekun. Tori wipe, Olorun ko ran omo re lati wa da araiye lejo, sugbon lati gba aye la nipa se omo re”.
Idariji – Nje o rorun bee?
Beeni, o rorun! Idariji ko see fi eto gba tabi ti owo ra lati odo Olorun. Ona ti o fi lee rii gba ni nipa igbagbo, ati pelu oore ofe ati aanu Olorun. Ti iwo ba fe gba Jesu Kristi gegebi Oluwa ati pe ki o gba idariji lowo Olorun, adura ti o le gba wa. Gbigba adura yi tabi adura miran nikan ko lee gba o. Igbekelee Jesé Kristi nikan ni o le mu idariji wa. Adura yii je ona lati fi igbagbo ninu Olorun han ati idupe lowo re fu nona ti o la fun idariji ese fun wa. “Olorun, mo mon wipe emi ti se si o ati wipe ijiya ni o ye fun mi lati, ti o fi je wipe nipa igbagbo ninu re (Jesu), emi yio ri idariji gba. Mo ya kuro, mo yipada ninu ese mi, mo si fi igbagbo mi sinu re fun igbala. Mo dupe fun iyanu oore-ofe ati idariji (Amin).
Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.
English
Bawo ni mo se le ri idariji gba lati odo Olorun?