settings icon
share icon
Ibeere

Nje eranko / ma n lo si orun? Nje eranko / ni emi?

Idahun


Bibeli o so fun wa nipa eyi, boya eranko ni “emi” tabi eranko yio wa ni orun. Sugbon, a le mu awon ori iwe Bibeli ki a si soro lori re. Bibeli ni wipe Enia (Genesisi 2:7) ati eranko (Genesisi 1:30; 6:17; 15:22) won ni emi aye. Eyi ti o fi yato si enia ati eranko ni wipe, a da enia ni aworan Olorun (Genesisi 1:26-27). A ko da eranko ni aworan Olorun. Dida enia ni aworan Olorun fi ye wa wipe a da bi Olorun, a le se ohun emi, pelu okan, emi-edun, ati ife - ati – ti a o si je eda leyin iku. Ti eranko ba ni “emi” tabi ohun ti a le lo, eyi yi o je ohun “iri” ti o kereju. Iyato si le je wipe “emi” eranko ko ni lo si orun.

Ohun kan miran ti a le so nipa ibere yi nipe Olorun da eranko gege bi ara ohun ti o da si ile aye ninu Genesisi. Olorunsi da awon eranko o si nipe o dara (Genesisi 1:25). Nitorina, ko si bi o ti le je wipe ki a ma ni eranko ni ile aye titun (Ifihan 21:1). A o si ri omiran ninu ile aye titun (Isaiah 11:6; 65:25). Ko si se-se ki a so wipe boya awon eranko yi yio je eyi ti a ni nigbati awa laye. A mon wipe olododo ni Olorun ati wipe ti awa ba de orun, a o ni ifowosowopo pelu ipinu lori oro yi, tabi ohun ti o ba je.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Nje eranko / ma n lo si orun? Nje eranko / ni emi?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries