Ibeere
Se o ti ni iye ainipekun?
Idahun
Bebeli fi ona iye ainipekun han. Ikini, a ni lati mo pe awa ti dese si Oluwa: “Gbogbo enia li o ti se, ti won si kuna ogo Olorun” (Romu 3:23). A ti se ohun a se ma se si Oluwa, iya ainipekun lo si to si wa. "Nitori iku li ere ese: sugbon ebun ofe Olorun ni iye ti ko nipekun, ninu Kristi Jesu Oluwa wa" (Romu 6:23).
Nitori na, Jesu Kristi, eni ti o dese (1 Peteru 2:22), omo Olorun ainipekun si di eniyan (Johannu 1:1,14) o si ku lati ra wa pada lowo iya aye wa, “sugbon Olorun fi ife on papa si wa han ni eyi pe, nigbati awa je elese, Kristi ku fun wa,” (Romu 5:8), Jesu ku fun wa lori igi agbelebu (Johannu 19: 31-42). Nitori naa o gba iya war a (2 Korinti 5: 21). Lehin ojo meta o si jinde (1 Korinti 15:1-4), to si fihan wipe o joba lori ese ati iku.” Eniti o tun wa bi, gege bi ajinde Jesu Kristi kuro ninu oku (1 Peteru 1:3).
Pelu igbagbo, a ni lati roun pwada, ki e sit un yipada, ki a le pa ese nyin re, ki a koko itura ba le ti iwaju oluwa wa (Ise Awon Apostoli 3:19). Ti a ba fi igbagbo wa fun, ni ireti ninu iku re ni ori agbelebu fun ese wa, yi o si darijiwa pelu ireti iye ainipekun. “Nitori oluwa fe araiye to be ge, ti o si omo bibi re kansoso fun ni, ki enikeni ti o ba gba gbo ma se segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun” (Johannu 3;16). “Pe, bi iwo ba fi enu re jewo Jesu li Oluwa, ti iwo si gbagbo li okan re pe, olorun ji i dide kuro ninu oku, a o gba o la” (Romu 10:9). Igbagbo nikan fun iparise Oluwa lori agbelebu nikan ni ona otito si iye ainipekun! Nitori ore-ofe li a ti fi gba nyin la nipa igbagbo: ati eyini ki ise ti enyin ti karanyin; ebun oluwa ni: ki se nipa ise, ki enikeni ma ba sogo’ (Efesu 2:8-9).
To o ba fe Gba Jesu Kristi gbo, lati je olugbala re, gba adura soki yi. Ranti, gbigba adura yi tabi adura miran ko le gba o. A fi ti o ba ni ireti ninu Kristi nikan ni o le gba o lowo ese. Adura yi je gege bi ona ti a file fihan si oluwa wipe a ni igbagbo ninu re ati pe a dupe lowo re fun pipe se irapada. “Oluwa, mo mon pe mo ti se si o ti o si to si iya. Sugbon Jesu Kristi gbe ese naa to to si mi ki n le ni ireti ninu re ki o si dari ese mi jimi. Mo si yi iwa pada ninu ese mi, mo si fi ireti mi le o lowo fun irapada. A dupe fun ore ofe yin to ga ati fun idariji ese- Ebun aye raye! Ami!”
Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.
English
Se o ti ni iye ainipekun?