settings icon
share icon
Ibeere

Kini esin kristiani ati wipe kini awon kristiani gbagbo?

Idahun


1 Korinti 15:1-4 so wipe, “Nje, ara, emi nso ihinrere na di mimo fun nyin ti mo ti wasu fun nyin, eyiti enyin pelu ti gba, ninu eyi tie yin si duro. Nipase eyiti a fi ngba nyin la pelu, bi enyin ba di oro ti mo ti wasu fun nyin mu sinsin, bikosepe eyin ba gbagbo lasan. Nitoripe siwaju ohun gbogbo mo fi eyiti emi pelu ti gba le nyin lowo, bi Kristi ti ku nitori ese wa gege bi iwe- mimo ti wi. Ati pe a sinku re, ati pe o jinde ni ijo keta gege bi iwe-mimo ti wi.”

Eyi ni igbagbo kristiani. Kristiani yato gan si awon igbagbo miran nitoripe kristiani je gege bi isepo, o yato si esin. Bi wipe ka so wipe ema se se ki e si se. “kristiani je ona ti oye ki a fir in pelu Oluwa Olorun wa. Aasepo yi je ki a mo nipa re nipa ti Jesu Kristi, ati ona re nipa emi mimo.

Kristiani gbagbo ninu Bibeli, oro Olorun, eko re si je ona otito naa ( 2 Timoteu 3;16, 2 Peteru 1; 20-21). Kristiani gba Oluwa kan gbo, ti o wa laye ti o si n be ni ona meta- Baba, Omo (Jesu Kristi ), ati Emi Mimo.

Kristiani gbagbo wipe a da wa ki awa le ni asepo pelu Oluwa, sugbon ese lo yaw a (Romu 5;12, Romu 3;23). Kristiani ko wa wipe Jesu Kristi rin orile ede aye yi, gege bi Olorun sugbon eleran ara enia ni (Ifihan 2; 6-11), o si ku lori igi agbelebu. Kristiani gbagbo wipe leyin iku re, won si si, o si jinde, leyin yi o si joko si apa otun Oluwa, ti o si gba adura wa (Heberu 7;25). Kristiani gbagbo wipe iku Jesu lori igi agbelebu san gbese ese wa, eyi si je ki a pada si odo Oluwa (Heberu 9; 11-14, Heberu 10;10, Romu 6:23, Romu 5;8 ).

Lati le ni igbala, iwo lati ni igbagbo ninu gbogbo ise owo Kristi lori igi agbelebu. Ti enikeni ba gbagbo wipe Kristi ku fun lati san gbese ese re, o si jinde, eni naa yio ri igbala. Ko si ohun ti enikeni le se lati ri igbala. Ko si eni ti o dara rara lati ri igbala gba, nitori pe elese ni wa (Isaiah 64; 6-7, Isaiah 53;6). Ekeji, ko si ohun ti o se, nitoripe Kristi si ti se gbogbo ise naa! Nigbati owa lori igi agbelebu naa, Jesu ni, “o ti tan”( Johannu 19;30).

Nitoripe ko si ohun ti o le se lati ri igbala, ti enikeni ba fi igbagbo re le Kristi lori igi agbelebu naa, eni naa ko le segbe. Ranti, ise naa ti pari lori igi agbelebu naa. Kristi! Ko si ohun ti o le se mo gege bi eni ti o gba gbogbo re; Johannu 10; 27-29 so wipe, “Awon agutan mi ngbo ohun mi, emi si mo won, nwon a si ma to mi lehin; Emi si fun won ni iye ainipekun; nwon ki o si segbe lailai, ko si si eniti o le ja won kuro li owo mi; Baba mi, eniti o fi won fun mi, po ju gbogbo won lo; ko si si eniti o le ja won kuro li owo Baba mi.”

Awon elomiran le ro wipe, Eyi dara- tie mi ba ti ni igbala, mo le se gbogbo ohun ti o ba wu mi, ki ma se segbe! “Igbala ki se nipaa ohun ti o ba fe lati se. Igbala je nipa wipe o fi gbogbo ese aye re sile ki o si ni ireti lati tele Oluwa. igbesi aye wa ni ile aye yi, le gan ni, nitoripe a tile sa fun ese wa ma nira. Ko ni je ka gbadun asepo Oluwa fun ohun ohun to o ni fun wa. Sugbon awon Kristiani le sa fun ese ti won ba n ka iwe Olorun ti a si ntele, ki emi mimo si n gbe ile aye wa- ki a fi gbogbo re le emi mimo ki o ba wa soro, ki a si pa ofin Oluwa mo.

Awon esin miran a ni ki se orisirisi si ohun lati le le tete tabi ki a ma se awon ohun kan, kristiani je gege bi asepo pelu Oluwa. Kristiani gbagbo wipe Jesu ku fun lori igi agbelebu fun ese wa, o si jinde. Gbese ese wa si ti di sisan, ki awa si tele Oluwa. iwo ni igbala lori ese re, rin pelu Oluwa, ki o si pa ofin re mo. Eyi ni otito bibeli kristiani.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Kini esin kristiani ati wipe kini awon kristiani gbagbo?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries