Ibeere
Bawo ni mo sele ni igbala ninu igbesi aye kristiani mi?
Idahun
Bibeli so nipa ohun won yi lati le ni igbala lori ese wa.
(1) Emi Mimo- ohun kan ti Oluwa fun wa (ile ijosin) lati ni igbala gege bi kristiani ti o ni Emi Mimo. Oluwa so nipa ohun ara ati titi emi ninu iwe Galatia 5:16-25. Ninu iwe na, o wi pe ki awa mar in ninu emi. Gbogbo onigbagbo ni o ni Emi Mimo, sugbon ori iwe yi ni wipe a ni latir in ninu Emi, nipa ona re. Eyi je gege bi wipe ki a ma fara sile sugbon ki si ma tele Emi Mimo yato si emi ara.
Ohun ti Emi Mimo le se ni inu aye onigbagbo la o ri ninu igbesi aye Peteru, ki o to ni Emi Mimo, o si se Jesu ni emeta, Leyin ti o si se eyi, o si ni wipe ohun yio tele Jesu de isa oku. Leyin igbati Emi Mimo wo un re, o si soro pelu igboya si awon ara Ju ni pentekosti nipa Olugbala.
A ma n rin ninu Emi lati m aje ki a kose (ki a pa ina Emi bi iwe 1 Tessalónika 5:19) sugbon ki e kun fun Emi Mimo (Efesu 5;18-21). Bawo ni enia se le ni Emi Mimo? Ikini, Oluwa ni kan ni ole fun wa gege bi o ti wa ninu iwe Maejemu Lailai. Yio mu eni ti o ba fe ati ohun ti o ba fe ninu iwe Majemu Lailai lati fun ni ise ti o fe ki won se (Genesisi 41:38; Eksodu 31:3; Numeri 24:2; 1 Samueli 10:10, bebe). Mo mo wipe o wa ninu iwe Efesu 5:18-21 ati kolosse 3;16 wipe Olorun ma n mu awon ti o ba fi oro Olorun sise ti o si je imuse. Eyi si mu wa wa si ona miran.
(2) Oro Olorun, iwe Bibeli – 2 Timoteu 3:16-17 so wipe, “ Gbogbo iwe-Mimo ti o ni imisi Olorun li o si ni ere fun ibani-wi, fun itoni, fun ikoni ti o wa ninu ododo. Ki enia Olorun ki o le pe, ti a ti mura sile patapata fun ise rere gbogbo. Heberu 4:12 so fun wa, E kiyesara, ara, ki okan buburu ti aigbagbo ki o mase wa ninu enikeni nyin, ni lilo kuro lodo Olorun alaye. Iwe Orin Dafidi soro nipa igbesi aye re-iyipada agbara ninu Orin Dafidi 119:9,11,105 ati imiran. Won so fun Josua wipe, a ti le ni igbala lori awon ota re ni iwe Mimo ti won fun wipe ki o si ma ka ni aro ati oru ki o ba le ye. O si se be, ohun ti Oluwa so fun gan nigba ogun ko ni itumo, eyi si ni kokoro igbala re ninu ogo ti o ja titi de ile ileri.
Eyi ni a ma fi han ninu ise wa. A se bi eni pe a ko ni ileri gidi ninu Bibeli naa, a gbe lo si ile ijosin, tabi ki a ma ka lojojumo, sugbon a ko rin ninu re, tele oro naa, bere fun idariji ese, ki si sin Oluwa, ki agbe ga fun ebun ohun ti o se fun wa. O da bi eni pe o ma n re wa tabi a ko jafara fun ohun ti a n ka ninu Bibeli. O da bi eni pe a ma fi se oye fun ara gege bi ti emi lati le wa laye ti a ba lo si ile ijosin, ( sugbon a ko fi gbe igbesi aye wa gege bi Omo Kristiani) tabi a ma n wa lati gba oro Olorun sugbon a ko n se asaro ninu re fun idagba ninu emi.
O se pataki pe ti iwo ko ba se asaro ninu oro Olorun ni ojo jumo fun ilosiwaju, ki o si mo si okan lati le je ki Emi Mimo gbajoba, ki o si ma se lojojumo. Ma gba ni imoran wipe ki o ni iwe kekere kan ti o le fi ma ko si le (tabi ero computa ti o ba le ko ni kiakia) tabi iwe miran, bebe. Se gege bi iwa lati mo ohun ti o ka tio si ye o. mo si ma n so fun Olorun ninu adura wipe ki o ran mi lowo nipa ibi aise dada mi. Bibeli ni ohun imulo fun igbesi aye (Efesu 6:17), eyi yi je ohun ija lati le bori awon ogun emi (Efesu 6:12-18)!
(3) Adura- Eyi je ohun mi ran ti Oluwa ti fi fun wa. Leyin naa, eyi ni awon Kristiani ma nso sugbon won ki lo daradara. A ma n pe jo lati gba adura, asiko adura, bebe, sugbon a ki n lo bi awon ara omo lehin Kristi ti se so (Ise Awon Aposteli 3:1; 4:31; 6:4; 13:1-3, bebe.). Paulu soro nipa awon ti ohun gba adura fun awon ti ohun wasu fun. A ki se, ti awa ba wa nikan, o ye ki a ma lo ohun ti o wa fun wa. Sugbon Oluwa ti se ileri gidi fun wa nipa adura (Matteu 7: 7-11; Luku 18: 1-8; Johannu 6:23-27; 1 Johannu 5:14-15, bebe.). Paulu si so ninu iwe re wipe ki a gbera di fun ogun emi (Efesu 6:18)!
Bawo ni o se se pataki to? Ti a ba wo Peteru, a ni oro Olorun pelu re ninu ogba Getsemane ki peteru to se. Nigba naa, bi Jesu ti n gba adura, se ni Peteru n sun. Jesu si ji, o fi fun pe, “E ma sona, ki e si ma gbadura, ki enyin ki o ma ba bosinu idewo; loto li emi nfe sugbon o se alailera fun ara” (Matteu26;41). Iwo bi Peteru, o fe se ohun ti o dara sugbon o ko ni agbara naa. A ni lati tele Olorun lati ma wa, ki a si ma kan ilekun, ki a si ma bere……. yi o si fun wa ni agbara ti a fe (Matteu 7:7). Sugbon a ni lati mo wipe a fe sin gidi gan ni.
Mi o so wipe adura je nkan bi oso. Ki se be. Oluwa dara gan ni. Adura je gege bi wipe ohun ti Oluwa fun wa lati ba soso ti a si mo wipe agbara Olorun ti ko ni opin ti a si ni igbagbo ninu re fun ohun ti o fe ki ase (ki ohun ti AWA fe se fun ra wa) ( 1 John 5:14-15).
(4) Ile ijosin- eleyi ji ohun miran ti a ko ko ibi ara si. Nigbati Jesu rana won omo leyin re jade, o ran lo ni meji meji (Matteu 10:1). Ti a ka nipa irin ajo awon oniwasu ninu Ise Awon Aposteli, won ko lo nigbakan na sugbon ni meji tabi ju be lo. Jesu wipe nibi ti enia meji tabi meta ba wa, ohun wa ni be (Matteu 18:20). O so fun wa pe ki ama se gbagbe ara wa bi akan se le gbagbe sugbon ki a ma ran ara wa lowo nipa ife ati ise rere ( Heberu 10: 24-25. O ni ki a si so fun ara wa ti a ba se (Jakobu 5:16). Nipa ti oye ati imoran ti iwe Majemu Lailai, won so fun wa wipe Irin a ma pon irin, be li okonrin ipon oju ore re (Owe 27:17) “ ati okun oniko meta ki iya faya.” Agbara wa ninu kika ohun. (Oniwasu 4:11-12).
Awon kan ti amo mo si ti ri arakunrin ninu Kristi tabi arabinrin ninu Kristi ( ti iwo baje arabinrin) won a si pade lati soro nipa bi igbesi aye won ti ri ninu Kristi, bi won se n tiraka, bebe. Won a si gba adura fun ara won, won a si gbin moran larin ara won lati ma se ohun ti Olorun fe ki won se.
Nigba miran nkan ma n yipada kiakia. Nigba miran, ni ibo miran, o le pe ki o to wa. Sugbon Olorun ti pinnu wipe ti a ba lo ohun ti o fun wa, yio se ohun iyanu ninu aye wa. Mo wipe olododo ni nipa ireti re!
English
Bawo ni mo sele ni igbala ninu igbesi aye kristiani mi?