settings icon
share icon
Ibeere

Nje ipase Kristi wa ninu Bibeli?

Idahun


Nipa ohun ti Jesu so nipa ara, awon omo leyin re si gba gbo nipa ipase re. Won ni agbara lati dari ji ese wa- nkan ti o je pe Oluwa nikan lo le se, eyi ti o fi je wipe a dese si (ise awon Aposteli 5:13; Kolosse 3:13; Orin Dafidi 130:4; Jeremiah 31:14). Pelu ohun ti a n jinyan re yi, Jesu naa ni won ni yio dajo awon ti o wa “laye tabi ti o ti ku” (2 Timoteu 4:1). Tomasi ki gbe pe Jesu, “Oluwa mi ati Olorun mi!” (Johannu 20;28). Paulu pe Jesu “Oba nla Olugbala” ( Titus 2:13), gege bi o ti wa si aye, o si “da bi Olorun” (Filemoni 2:5-8). Eni ti o ko si Heberu nipa Jesu wipe, Ite re, Olorun, lai ati lailai ni” (Heberu 1:8). Johannu wipe, Li atetekose li Oro wa, Oro si wa pelu Olorun, Olorun si li Oro (Jesu) na” (Johannu 1;1). Eyi ti o wa ninu iwe mimo ti o ko wa nipa ipase Kristi le di pipo (wo Ifihan 1: 17; 2:8;22;13 1 Korinti 10:4; 1 Peteru 2:6-8. Orin Dafidi 18:2; 95:1; 1 Peteru 5:4; Heberu 13:20), sugbon e yi ye ki o je ki awon enia fi mon nipa ipase re pelu awon omo leyin re.

Jesu si awon Oruro miran bi Yahweh (Oruro ti Olorun n je tele) ninu iwe majemu lailai. Majemu lailai wipe “Oludande” (Orin Dafidi 130;7, Hosea 13:14) ni won lo fun Jesu ninu majemu Titán ( Titu 2: 13; Ifihan 5;9). Wo pe Jesu ni Emmanueli (“Oluwa wa pelu wa” ninu Matteu 1). Ninu iwe Sekariah 12:10, yahweh ni o so be, “ Nwon o ma wo eniti a gun li oko.” Sugbon iwe majemu titán li o so eyi nipa kikan mo agbelebu re (Johannu 19;37; Ifihan 1:7). Ti o b a je wipe yahweh ni won gun ni oko, ti won si wo, ti o si je wipe Jesu ni won gun ni oko ti won si wo, Jesu si ni Yahweh naa. Paulu so ninu Isaiah 45:22-23 nipa Jesu ninu Filippi 2;10-11. Leyin naa, a lo oruko Jesu pelu yahweh ninu adura “Ore-ofe si nyin ati alafia lati odo Olorun Baba wa, ati Jesu Kristi Oluwa wa’ (Galatia 1;3, Efesu 1:2). Eyi a je oro odi ti ipase Kristi o ba wa. Oruko Jesu je gege bi Yahweh ti Jesu ti pase wipe ki a se irubomi ni oruko (le kan soso) ti Baba ati Omo ati Emi Mimo” ( Matteu 28:19 wo 2 Korinti 13:14).

Ohun ti Oluwa le se ni amo si ise re. Jesu ko ji oku dide nikan (Johannu 5: 21; 11:38-44), o si dariji ese wa (Ise Awon Aposteli 5;31; 13:38), od gbogbo aye ati ohun kohun (Johannu 1:2; Kolosse 1:16-17)! Eyi je ki amo gidi gan wipe ti a ba wo oro Yahweh wipe o si ti wa latetekose (Isaiah 44:24). Kristi ni awa ohun iwa ti o je wipe eni ti o ni iru ipase yi ni o le ni. Ayeraye (Johannu 8:58), o wa pelu wa ni igbagbogbo (Matteu 18:20, 28:20), o mo ohun gbogbo (Matteu 16:21), O le se ohun gbogbo (Johannu 11:38-44).

Ni isin yi, ki awon kan so wipe Olorun ni awon tabi ki a paro fun awon kan wipe otito ni, ki a si wa ohun ti a fi ma jiyan re. Kristi fihan wa wipe ohun ni ipase oro gege bi ise iyanu re, ati ajinde re. O si se ise iyanu bi o si ti yi omi si oti wini (Johannu 2:7), o rin lori omi (Matteu 2:3), ati awon alaisan (Matteu 9:35; Maku 1:40-42), ti o si ji oku dide (Johannu 11:43-44; Luku 7:11-15; Maku 5:35). Jesu si jinde. Eyi ti a mon ti o si yao si awon olorun miran ti won le jinde- ko si si wipe a gbo nipa re. Bi Dokito Gary Haberlas se so, awon bi ohun mejila lo fi han si awon keferi nipa ajinde re:

1. Jesu ku nitori a kan mo agbelebu
2. A si sin
3. Iku re je ki awon omo leyin re wa ninu ironu ati irota.
4. Isa oku Jesu wo si ri wipe o sofo lyin ojo die.
5. Awon omo leyin re si mo wipe awon ti ri ajinde Jesu.
6. Leyin eyi, awon omo leyin re si ni okun ati agbara lati sise.
7. Eyi ni iwasu larin awon ijo nigbati won bere
8. won si wasu oro yi ni Jerusalemu.
9. Nitori iwasu yi, a si kede ibere ile ijosin ti o si gboro.
10. Ojo Ajinde, Sunday, ti o yato si Sabati (satiday) ti a mo si ojo ijosin
11. Jakobu, ti ko ni igbagbo, si di atunbi ni igba ti o ri ajinde Jesu.
12. Paulu, ota Kristiani, si gbagbo nipa ohun ti o mon nigbati o pade ajinde Jesu.

Nje ti enikeni ba wi pe iro ni gbogbo ohun ti mo ti so yi, awon die ni a le fihan lati le je ki won mon bi, ajinde re ati iroyin ayo: Iku Jesu, sisin re, ajinde ati riri re (1 Korinti 15:1-5). A si mon wipe orisirisi ni a le fi han nipa ohun ti mo ko yi, sugbon ajinde re ni o dahun gbogbo ibere naa. Awon enia so wipe awon omo leyin re wipe won ri ajinde Jesu. Bi o ba je iro tabi a n ro, ko si ohun ti o le yi oj okan pada gege bi ajinde re. Ikini, ki ni ere won? Kristianiti o je ki won ni ola ati owo. Ekeji, awon oniro o le jinyan fun ohun ti a ba ti wa tele. Ko si ohun miran sugbon ajinde re ti awon omo leyin Jesu gbagbo ti won si le ku sibe. Beni, orisirisi awon enia ni o ti ku nipa iro ti won pa ti won si ro wipe otito ni sugbon ko si eni ti yio ku fun ohun ti won gbagbo.

Ni soki, Kristi so wipe Yahweh ni ohun, ohun ni ipase (lai se “olorun” nikan- sugbon Olorun otito), awon omo leyin re (awon Ju ti o ye ki won beru irubo) gbagbo, won si tele. Kristi fi han wa wipe ohun ni ipase ise iyanu nipaajinde re. Ko si enikeni ti o le fi eyi han.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Nje ipase Kristi wa ninu Bibeli?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries