Ibeere
Tani iyawo Kaini? Nje iyawo Kaini je gege bi aburo re?
Idahun
Bibeli ko so fun wa eni ti iyawo Kaini je. Nkan ti a le so ni wipe iyawo kaini je gege bi aburo re tabi ebi re, bebe. Bibeli ko so fun wa nipa odun re nigbati o pa Abeli (Genesisi 4:8). Nitoripe won je agbe, won si ti dagba pelu ebi ti won. Adamu ati Efa si ti bi omo miran nigbati o si pa Abeli- won bi omo si lehin naa (Genesisi 4:14). Nitoripe, Kaini beru emi ara re leyin ti o pa Abeli (Genesisi 4:14) eyi fi han wipe won si bi omo miran tabi omo mo Adamu ati Efa nigba naa. Iyawo Kaini (Genesisi 4:17) je gege bi omo obinrin tabi omo mo Adamu ati Efa.
Nitoripe Adamu ati Efa je akoko (awon nikan) omo enia, omo won ni lati fe ara won. Olorun ko lodi si wipe ki a fe ebi ara wa sugbon leyin igba ti fife ra wa di ohun ti ko wulo mon (Lefitiku 18:6-18). Ohun ti ko fi dara ki egbon ati aburo fe ra won ni wipe awon omo won yio ni eje ila kan naa. Ti awon enia ti o ba wa lati ebi miran ba fe ara won- awon obi won ko le ni ohun ila eje kan naa. Awon enia si ti so eyi di ohun apapo, ohun ilo ti o je wipe lati iran kan si iran ni won si ti so eyi di ohun miran. Adamu ati Efa o ni aisan kankan ninu eje won, eyi si je ki won le ni omo to dara yato si awa nisinyi. Omo Adamu ati Efa ni arun die. Nitori naa, won le fe ara won. Ni ibere, nigbati Olorun bere pelu okunrin kan ati obinrin kan, nitori naa, iran keji ni lati fe ara won.
English
Tani iyawo Kaini? Nje iyawo Kaini je gege bi aburo re?