Ibeere
Nje o ye ki ababirin je alufa / oluso-aguntan? Kini Bibeli so nipa obinrin gege bi iranse?
Idahun
Ko si ohun ibere ni ile ijosin jun wipe se o dara ki arabinrin je iranse ni ile ijosin. E ma se wo ibere yi gege bi igagbega pelu okunrin. Awon obinrin miran gbagbo wipe ko ye ki obinrin je iranse, o si wa ninu bibeli- Awon okinrin miran si gbagbo wipe ara binrin le je iranse ninu ijosin ko si si ohun ti o da won duro. Eyi ki se ami oto tabi ikorira re. Sugbon nipa ohun ti Bibeli so.
1 Timoteu 2:11-12 wipe, “ Je ki obirin ki o ma fi idakeje ati iteriba gbogbo ko eko. Sugbon emi ko fi ase fun obirin lati ma koni, tabi lati pase lori okonrin, bikosepe ki o dakeje.“ Ninu ile ijosin, Olorun pin ise orisirisi fun okonrin ati obirin lati se. Eyi je nipa bi a se da wa (1 Timoteu 2:13 ) ati bi ese se wa si ile aye (2 Timoteu 2:14). Olorun, gege bi Aposteli Paulu se so wipe, obirin ko gbodo je iranse ninu ile ijo lori okonrin. Eyi o si je ki awa arabirin je iranse, oniwasu, iko ni leko, ati agbara emi lori okonrin.
Orisirisi “isodi” lo wa lori oro yi nipa obirin irase / oluso-aguntan. Eyi ti a mon ni wipe, paulu so wipe obirin ko gbodo se iru ise yi nitoripe ni aye atejo won ko ka we. Sugbon, 1 Timoteu 2:11-14 ko so fun wa nipa eyi. Ti eko b aje ohun tani lati se ise iranse, eyi o si fi han wipe opolopo omo lehin Kristi o ni le se ise naa nitoripe won ko kawe. Ekeji niwipe, paulu so fun awon ara birin Efesu nikan lati ma sise Olorun. (1 Timoteu ni a ko si Timoteu, ti o si je alufa ni Efesu). Amon ilu Efesu fun tempili Atemi, orisa orisirisi. Awon obinrin ni o wa ni idi awon orisa yi ni Atemi. Sugbon iwe 1Timoteu ko so fun wa rara nipa Atemi, tabi Paulu so wipe nitori ohun ti won n sin ni a se so wipe won kogbodo je iranse.
Ohun iketa niwipe, Paulu n so nipa oko ati aya, ki se okonrin tabi obirin. Oro Greeki nini 1 Timoteu 2 :11:14 le je Okonrin tabi obirin. Nitornaa oro naa le je okonrin tabi obirin. Oro Greeki naa latun lo ni ori 8-10. Nje awon okonrin nikan ni ole gbe owo Mimo so ke lase pe ninu ibinu tabi ija (ori 8)? Nje ki obirin mura dada, ni iwa dada, ki won si sin Olorun (ori 9-10)? Rara. Ori 8-10 so nipa okonrin ati obirin, ki se oko ati aya nikan. Ko si ohun kan ninu ori iwe naa wipe a le yipada ni ori 11-14.
Ohun miran ti o si je ki a ni ibere lori oro yi naa ni Miriami, Debora, Hulda, Prisilla, Foebe, bebe, - awon obirin ti won je olori ninu ile ijosin. Eyi ko je ki won so ni pato nipa re. Nipa Debora, ohun je arabirin nikan larin awon adajo okonrin metala. Hulda, ohun nikan ni woli arabirin larin woli arakonrin mejila ninu Bibeli. Nitori pe Miriami je aburo Mose ati Aroni ni o fi je wipe o je asaju. Awon meji ti atun le so ni asiko oba naa ni Atalia ati Jezebel- a ko le so wipe asaju ni won.
Ninu iwe Awon Ise Aposteli, ori 18, Priskilla ati Akuila je asiwaju olododo niwaju Olorun. Akoko da ruko Priskilla, nitori pe o je eni Kete-kete ju oko re lo. Sugbon a ko da oruko Priskilla wipe o nse ise ijo ti o fi han ninu iwe 1 Timoteu 2 : 11-14. Priskilla ati Akuila mu Apollo wa si ile won, won si ko ni ona otito ti Olorun (Ise Awon Aposteli 18:26).
Ninu Romu 16:1, ti a ba ni pe Foebe je oye arabirin “diakoni” lai se “iranse”- eyi ko so wipe o je oluko ni ijo. “Ki a le koni” je ipo fun awon agba, sugbon ki se fun diakoni (1 Timoteu 3:1-13; Titu 1:6-9). Awon agbagba / olori alufa / diakoni ni a mon si “oko ti iyawo kan” “okonrin ti awon omo re gbagbo,” ati “awon okonrin ti a ni owo re.” Ni apapo, 1 Timoteu 3:1-13 ati Titu 1:6-9, ako oro ni an lo fun agbagba / olori alufa /diakoni.
Bi a se ko 1 Timoteu 2:11-14 fun wa ni “idi” oro yi. Ese 13 bere pelu “nitori” o si fun wa ni “idi” ti Paulu fi so ni ese 11-12. Ki ni o de ti awon arabirin o le je oluko tabi ni ipase lori okonrin? Nitoripe- “ a koko da Adamu, leyin naa Efa. Sugbon Adamu ko ni won tan; bikose Efa ni a tan.” Eyi ni otito. Olorun da Adamu ni akoko, o si da Efa tele geg bi “oluranlowo” fun Adamu. Eyi je ona imole ati otito ni ile aye, ninu ebi (Efesu 5:22-33) ati ile ijo. Nitori pe won tan Efa, eyi fi han naa wipe awon arabirin o le je oluko tabi ni ipase lori okonrin. Awon elomiran si gbagbo wipe obirin o si gbodo je oluko nitoripe a le tan won. Eyi je ohun ijiyan…. sugbon ti a ba le tan obirin, ki ni o de ti won fi n ko awon omode (Ti won se tan) ati wipe awon obirin miran (ti a le tan)? Eyi ko so bee. Obiri ko gbodo je oluko tabi ni ipase emi lori okonrin nitoripe Efa je eni ti a tan. Gege be, Olorun ti fun awon okonrin ni ase lati je oluko ninu ijo re.
Awon obirin mon ise itoju se, anu, ikoni ati iranlowo. Pupo ninu ise ijo wa lowo obirin. A ko si lodi si wipe ki awon obirin ma gba adura ni gbangba tabi ki won ma riran (1 Korinti 11:15), sugbon ki won ma se ni ase lori okonrin. Bibeli o ni pe ki awon obirn ma se ise ebun ti Emi Mimo fi fun won (1 Korinti ori 12). Obinrin, bi okonrin naa ni ape lati se ise Olorun, lati fi eso emi naa han (Galatia 5:22-23), ki a si kede iroyin ayo fun awon ti o ti sonu (Matteu 28:18-20; Ise Awon Aposteli 1:8; 1 Peteru 3:15).
Olorun si ti pe okonrin nikan lati wa ni ipo oluko ti emi ninu ijo re. Eyi ko so wipe awon okonrin je oluko gidi ju obirin lo, tabi obirin rele ju tabi won ko ni ogbon to won (eyi ko je be). Eyi je bi Olorun se se iro ijo re. Okonrin ni lati fi apere han ninu ijo- ninu igbesi aye won ati oro won. Obirin ni lati ma tele won lati sise. Obirin si le ko obirin (Titu 2:3-5). Bibeli naa ko si wipe ki obirin ma ko awon omode. Ohun ti obirin ko le se ni ki won je oluko tabi ki won ni ase lori okonrin. Eyi si wa lara re pe ki won ma je alufa / woli. Eyi ko so wipe obirin je awon ti ko se pataki, sugbon fun won ni ise iranse nipa ebun ti Olorun ti fi fun won.
English
Nje o ye ki ababirin je alufa / oluso-aguntan? Kini Bibeli so nipa obinrin gege bi iranse?