Ibeere
Kini Bibeli so nipa eranko bi alangba yi? Nje eranko nla atijo yi wa ninu Bibeli?
Idahun
Bi Bibeli ti wi, lati igba adaye, awon Kristiani ti n soro fun igba die ati bawo ni a sele dahun ohun ti o wa ni ayika wa. Bibeli ko soro fun nipa iru eranko nla yi, nitoripe won ti ku tipe ki omo eniyan to rin lori ile aye yi. Awon to ko Bibeli won ko ri iru eranko yi.
Awon to gbagbo ninu pe ile aye wa je ewe, gba wipe Bibeli ko so nipa eranko nla yi. Bikosepe won pe won ni Tanniyini. Ohun ti a n pe ni Tanniyini yato si bi a se pe ninu Bibeli; a le pe ni ohun “ibanileru omi” a tun le pe ni “ejo nla.” A le pe ni “eranko oniwo.” Tanniyini je eranko ti o tobi . A daruko eranko yi ninu Majemu Lailai ni ogbon igba ti a le ri ni ori ile ati omi.
Bi a se wi pe a daruko re ninu Majemu Lailai ni ogbob igba, Bibeli fi han nipa eranko yi ti o je wipe awon akowe ro wipe a n soro nipa eranko bi alangbayi. Behemoti ni won n pe, o ni agbara ninu eranko ti Oluwa da, o sit obi gan, iru re si gun bi igi. (Jobu 40;15). Awon elomiran si pe Behemoti ni eranko bi erin tabi esin odo. Won ni erin ati esin odo ni iru ti o tiring, ko si ohun ti o dabi igi. Iru eranko yi bi Barachosarusi ati Diplokusi ni iru ti o dabi igi.
Lati igba si igba awon ti o ya aworan si ti fi han ninu ise won. Petroglyphs, ayaworan, pelu amo ti won fi n ya aworan ni ilu gusu Amerika jo eranko yi. Okuta gbigbe ni gusu Amerika, fun Triceratops,-Pretrodactyl,-ati Tyrannosaurusi bi eranko. Awon akose ti Romu, ati orisirisi fi han wipe awon eranko yi ti wa tipe. Eyi ti a mon si Marco Polo keji ki awon naa wipe awon eranko yi ni itan tiwon.
Gege be naa ti a si ti mon wipe omo enia ati eranko yi si jo wa, a tun ni awon ohun miran ti o le fihan wa, ohun bi ila ese ti enia ati eranko ni ariwa Amerika ati ibomiran.
Ti a ba wo, nje eranko yi wa ninu Bibeli? A ko ti pari oro naa. Ti a ba si wo, iwo le wipe eranko yi wa tabi ko si. Nibi eyi ti ani ibere, a gbagbo wipe awon eranko yi wa pelu enia. A gbagbo wipe awon eranko yi pelu eniyan. A gbagbo wipe eranko yi wa won si ti ku tipe leyin omiyale ati wipe awon eniyan pa won naa.
English
Kini Bibeli so nipa eranko bi alangba yi? Nje eranko nla atijo yi wa ninu Bibeli?