settings icon
share icon
Ibeere

Ibalopo- Nje o je ese gege bi Bibeli?

Idahun


Bibeli ko daruko ibalopo tabi ibalopo je gege bi ese. Ko si ibere, sugbon, yala boya iwa ti o mu eyi je ese. Ibalopo je gege bi opin ifekufe okan, tabi iran ibalopo. Eyi je ohun ayewo ti a ni lati se iyipada. Ti ese ifekufe ati iran ibalopo ba ti dopin- ayewo ibalopo yio je ohun kekere lati fi sile.

Bibeli so fun wa wipe ki a sa fun ohun ti o da bi agüere (Efesu 5:3). Mi o mon bi ibalopo naa se le yato si ese miran. Nigbamiran ti o ba fe mon ohun rere ti o se, a man n so fun awon elomiran. Ti o baje sisu ki awon enia ma mon, eyi yi yio je ese. Nkan miran ni wipe, se a le so fun Olorun ki o bunkun wa, ki o si lo iru iwa yi fun ona otito re. Emi k oro wipe ibalopo je ohun “igberaga” tabi ohun ti a le dupe lowo Oluwa fun.

Bibeli ko wa wipe, “Nitorina bi eyin ba nje, tabi bi enyin ba nmu, tabi ohunkohun ti eyin ba nse, e ma se gbogbo won fun ogo Olorun” (1 Korinti 10:31). Ti ohun aye ba wa lati so wipe o dun mo Olorun, o si ye ki a fi sile. Sugbon iyemeji wa fun ibalopo. “Ohun ti o baje ti igbagbo ese ni” (Romu 14:23). A ko ri, gege bi Bibeli, ibalopo ara se le gbe ogo Olorun ga. Siwaju, a ni lati ranti wipe ara wa, ati emi wa, ti di irapada o si wa fun Olorun. “Tabi, eyin ko mo pe ara nyin ni tempili Emi Mimo, ti mbe ninu nyin, ti enyin ti gba lowo Olorun? Enyin ki si ise ti ara nyin, Nitori a ti ra nyin ni iye kan: nitorina e yin Olorun logo ninu ara nyin, ati ninu emi nyin, ti ise ti Olorun” (1 Korinti 6:19-20). Eyi je otito lati mo ohun ti a n se, ibi ti asi n lo pelu ara wa. Nitorina, gege bi eyi ti a ti so, emi yio si so wipe ibalopo je ikorira si Olorun, sa fun ohun agüere, tabi se aseyori ninu idawo Olorun ki o si ni olohun lori ara re.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Ibalopo- Nje o je ese gege bi Bibeli?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries