Ibeere
Kini Bibeli so nipa ibaraasun siwaju igbeyawo?
Idahun
Pelu gbogbo ohun ise agbere, ibarasun siwaju igbeyawo je ohun ti ko dara gege bi Bibeli (Ise Awon Aposteli 15:20; Romu 1:29; 1Korinti 5:1; 6:13;18; 7:2; 10:8; 2 Korinti 12:21; Galatia 5:19; Efesu 5:3; 1 Thessalonika 4:3; Juda 7). Bibeli ni kia pa ara wa mo siwaju igbeyawo. Ibarasun je ikorira gege bi iwa-pansaga ati agbere miran, gbogbo e naa si je ibarasun siwaju igbeyawo. Ibarasun larin oko ati aya nikan ni Oluwa wi (Heberu 13:4).
Ibarasun siwaju igbeyawo wopo ni ona gbogbo. O ye ki a gba ni iyewo bi eyi se je ohun ti o jasi. Ni toto, ibarasun dara gan. Oluwa si si be. O fe ki okunrin ati obirin ki won gbadun re (larin igbeyawo). Sugbon, idi ti Oluwa fi da ki se nipa igbadun, sugbon ki a loyun ti awa ko fe, tabi obi ti ko fe omo naa tabi won ko setan lati to. Bawo ni o se ma dara to ti awa ba tele ona yi; arunkarun ko nip o, awon obirin ti ko se igbeyawo won nip o, oyun ti ako fe ko nip o, iseyun ko nipo, bebe. Ki a sis a fun ni Oluwa fe nipa eyi. Ti a ba se eyi, ile aye wa yio dara, a o dabobo boa won omo titun, a o si mo ohun ti oye ki a se nipa ibasun, ati ni Pataki ki a fun Olorun ni owo.
English
Kini Bibeli so nipa ibaraasun siwaju igbeyawo?