settings icon
share icon
Ibeere

Kini igbese igbala?

Idahun


Se e bi n pa o? ki se ni pa ebi ti ara, sugbon se ebi n pa o fun ohun kan ninu aye? Se ohun kan wa ninu okan re ti o fe ohun titun? To ba je be, Jesu ni ona naa! Jesu wipe, “Emi ni onje iye; enikeni ti o ba to mi wa ebi ki yio pa a; eniti o ba si gba mi gbo, orungbe ki yio gbe e mo lai” (Johannu 6:35).

Ko ye o bi? Iwo ko ni ona tabi ile aye re ko ni idi? Se o dabi wipe enikeni to pa ina aye re ko si si bi o se le tan? To ba je be, Jesu ni ona naa! Jesu wipe, “Emi ni imole aiye; eniti o ba to mi lehin ki yio rin ninu okunkun, sugbon yio ni imole iye” (Johannu 8:12).

Se ile aye dabi pe won ti tie mota? Se o ti si orisirisi ilekun to je wipe ofo ati pe ko ni itumo, ohun ti o ba nibe ni yen? Se iwo n wa ilekun si ona igbesi aye gidi? To ba je be, Jesu ni ona naa! Jesu wipe, “Emi ni ilekun; bi enikeni ba ba lati pa, ati lati parun emi wa ki nwon le ni iye, ani kin won le ni lopolopo. Eni naa yio wole, yi o si jade, yi o si ri ohun rere” (Johannu 10;9).

Se awon enia ti dotu tio o ri? Se ilopo re pelu awon enia re ja si asan? Se o da pea won eniyan fe ma lo e fun elo ti won? To ba je be, Jesu ni ona naa! Jesu wipe, “Emi ni oluso-agutan rere, oluso-agutan rere fi emi re lele nitori awon agutan……. . Emi ni oluso-agutan rere, mo si mo awon temi, awon temi si mo mi” (Johannu 10;11,14).

Nje iwo mo ohun ti yio sele leyin aye yi? Se o ti su o lati ma gbe ile aye ti o le tabi ti koro? Se iwo ro wipe ile aye yi ko ni itumo? Se iwo fe ni aye ti o baku? To ba je be, Jesu ni ona naa! Jesu wipe, “Emi ni ajinde ati iye; enitio ba gba mi gbo, bi o tile ku, yio ye.” Enikeni ti o mbe laye, ti o si gba mi gbo, ki yi o ku lailai. Iwo gba eyi gbo (Johannu 11:25-26).

Kini ona naa? Kini otito naa? Kini ile aye yi? Jesu wipe, “Emi ni ona naa, otito ati iye. Ko si enikeni ti o wa sodo Baba mi bikose nipase mi” (Johannu 14;6).

Ebi ti o n pa o, ebi emi ni, Jesu nikan lo le fun o. jesu ni kan ni o le gbe gbogbo okunkun re kuro. Jesu ni ilekun to o le fun o ni igbesi aye rere. Jesu ni ore ati oluso-agutan ti o n wa. Jesu ni aye- ni ile aye yi ati eyi ti on bo. Jesu ni ona igbala!

Idi tie bi fi n pa o niwipe, iwo ti wa ninu okunkun, idi ti iwo o fi mo boya ile aye ni itumo ni wipe, iwo ti jina si Olorun. Bibeli wipe, elese ni gbogbo wa nitori naa a si ti jina si Oluwa (Iwe Oniwasu 7:20; Romu 3:23) ohun ti o n wa ninu aye re ti ko si nibe ni Oluwa. A da wa ki awa le ni ibase po pelu oluwa. Nitori ese wa, awa si ti jina si ibase po naa. O buru bee, ese wa le je ki a pinya patapata si Oluwa titi ayeraye, ni isinyi tabi eyi ti o n bo.

Ba wo ni isoro yi se le yanju? Jesu ni on naa! Jesu gbe ese war u ( 2 korinti 5;21). Jesu ku fun wa (Romu 5; 8) o si gbe iya ese wa ru. leyin ojo meta, Jesu jinde ninu oku, o si fihan nigba ti o joba lori ese ati oku ( Romu 6:4-5). Ki ni o de ti a fi se? Jesu dahun ibere naa fun ara re, “ko si enikeni ti o ni ife ti o tobi ju eyi lo, pe enikeni fie mi re lele nitori awon ore re’ (Johannu 15; 13). Jesu ku nitori ki awa le wa laye. Ti awa ba fi igbagbo wa sinu Jesu, otito ninu iku ati gbese ti o san fun ese wa- gbogbo ese wa ti dariji o si ti we wa. Igba naa ni awa yi o ni ebi emi wa gba. Imole yi o si tan. Awa yi gbe igbe aye ti o ni itumo. Awa yi o ni ore olotito ati oluso-agutan gidi. Awa yi o mo wipe a o wa laye leyin ti a ba ku- ajinde emi ni orun fun ainipekun pelu Kristi.

“Nitori Olorun fe araiye to be ge, ti o fi Omo bibi re kan soso fun ni, ki enikeni ti o ba gba agbo ma ba segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun” (Johannu 3; 16).

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Kini igbese igbala?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries