settings icon
share icon
Ibeere

Ṣé ó yẹ kí Kristiẹni máa ní sùúrù nípa ìgbàgbọ ẹsín ti ẹlòmíràn?

Idahun


Ní àkókò ti wa ''sùúrù,'' ìwà àtìlẹhìn ti di kíkà sí bíi ìwà rere tí ó ga jùlọ. Gbogbo ẹ̀kọ́, èrò, àti ètò ìgbàgbọ ní àǹfàní kan náà, ní alátìlẹhìn ńsọ, tí ò sí jẹ ìtọsí ìbọwọ kan náà. Àwọn tí ó ṣe ojú rere ètò ìgbàgbọ kan lórí òmíràn tàbí—yálà burú jùlọ—ńgbà ìmọ òtítọ́ pọnbélé tí a kà sí ìrònú-ọlọnà tóóró, àìní ìlanilọyẹ, tàbí bóyá àinì sùúrù.

Ní òtítọ́, oríṣiríṣi ẹsìn ńmú gbígba ìbámu ẹkúnrẹrẹ ṣẹ, àti alátìlẹhìn náà kò lè ṣe ìbálàjà tí ó ní ìrònú sí àíbáramu gédéngbé. Fún àpẹrẹ, Bíbélì náà jẹ kí a gbà wípé ''ènìyàn ti yàn láti kú l'ẹẹkan ṣoṣo, àti lẹhìn èyí wípé ìdojúkọ ìdájọ ni'' (Heberu 9:27), nígbà tí àwọn ẹsìn díẹ kan láti ìla òòrùn ń kọ ni ní àkúdàáyà. Nítorí náà, ṣé a kú ní ẹẹkan tàbí ní púpọ ìgbà? Àwọn ìkọni méjèèjì kò lè jẹ òtítọ. Alátìlẹhìn náà ń ṣe àyípadà pàtó sí òtítọ ní ìgbìyànjú láti ṣẹdá a ayé tí kò báramu ní ibi tí púpọ ìlòdì ''òtítọ'' lè wà ní ìbágbépọ.

Jésù sọ wípé, "Èmi ni ọnà òtítọ àti ìyè náà. Kò sí ẹni tí ó lè wá sọdọ Baba bíkòṣe nípasẹ mi." (John 14:6). Kristiẹni kan ti gba Òtítọ́, kìí kan ṣe gẹgẹ bí àkọsílẹ, ṣùgbọn bí Ènìyàn. Gbígba àwọn òtítọ yìí ń mú ìjìnà Kristiẹni náà lọwọ irúfẹ ''ọkàn lílà'' tí òde òní. Kristiẹni ti gbà ní gbangba wípé Jésù ti jí dìde kúrò nínú òkú (Romu 10:9-10). Bí ó bá gbàgbọ nínú àjíndè, báwo ni ó ṣe lè jẹ "ọlọkàn lílà'' nípa ìdánilojí t'aílàgbágbọ kan wípé Jésù kò jí dìde mọ rárá? Fún Kristiẹni tó lè sẹ ìkọni Ọrọ Ọlọrun kedere yíò jẹ dída nítòótọ ti Ọlọrun.

Kíyèsi wípé a ti ṣe àpẹẹrẹ àwọn kókó ìpìlẹ ti ìgbàgbọ́ nínú àwọn àpẹẹrẹ wa dé ìhín. Àwọn ohun díẹ kan (bíi àjíǹde ara ti Kristi) jẹ èyí tí kò ní ìdúnà dúrà. Àwọn ohun míìrán lè wà níṣínṣínyí fún àríyànjiyàn, gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí o kọ ìwé ti Hébérù tàbí àbùdá ti "ẹgún ti ńbẹ l'ára" Pọọlù. A gbọ́dọ̀ yẹra ní dídi ìrẹsílẹ nínú àwọn ìjà lórí àwọn ọ̀rọ̀ tí atẹlé (2Timoteu 2:23; Titu 3:9).

Kódà nígbà tí ìjà/ìtakùrọ̀sọ lóri àwọn ẹ̀kọ́ tí ó gbòde kan, Kristiẹni gbọ́dọ̀ ṣe ìkóra ẹni níjànu kí ó sì fi ìbọ̀wọ̀ hàn. Ó jẹ́ ohun kan láti má gbà pẹlú ipò kan; ó tún jẹ nǹkan míìrán láti ṣi ènìyàn kan ní ipò. Àwá gbọ́dọ̀ di èyí tí ó jẹ́ Òtítọ́ mú ṣinṣin nígbàtí a bá ńfi àánú hàn sí àwọn tí ó bá takó ó. Gẹ́gẹ́ bíi Jésù, a gbọ́dọ̀ kún fún ore-ọ̀fẹ́ àti òtítọ́ (Johannu 1:14). Peteru ṣe ìwọntúnwọnsì tí ó dára láàrín níní ìdáhùn àti níní ìrẹlẹ. "Má a wà ní ìgbáradì láti fi ìdáhùn fún gbogbo ènìyàn tí ó ńbí ọ léèrè láti fún wọn ní ìdí fún ìrètí tí o ní. Ṣùgbọn ṣe eléyìí pẹlú ìwà pẹlẹ àti ìbọwọ" (1 Peteru 3:15).

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Ṣé ó yẹ kí Kristiẹni máa ní sùúrù nípa ìgbàgbọ ẹsín ti ẹlòmíràn?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries